한국   대만   중국   일본 
Obiripo - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Obiripo

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Obiripo

Ninu mathimatiki obiripo (Circle) pelu arin C ati ilatotan r, je irisi aniwonile to je akojopo awon ojuami ati ijinasi won si arin ti a n pe ni ilatotan (radius).

Iyipo je Ila-alajapo (curve)ti o ti; ti o si pin pepe si apa inu ati ode. Ibu re ni a mo si ayika (circumference). Inu re ni a n pe ni ab?? (disk). ?fa (arc) si ni apa iwapapo pato kan lori iyipo na.

Agbeyewo [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Idogba fun iyipo [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Ti a ba ni ona ipoidojuko x-y , iyipo to ni arin ni ( a , b ) ati ilatotan r je akojopo gbogbo ojuami ( x , y ) to fi je pe

Ti o ba je pe ni ojuibere ( 0 , 0 ) (origin) ni arin re wa, a le so afise dero bayi,


Be si ni tangenti yio je


nigbati , si je ipoidojuko ojuami kanna won.


( x y )


Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]