Maj??mu Titun

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Maj??mu Titun

Maj?mu titun [note 1] ni ipin keji ti Bibeli mim? Krist?ni. O s? nipa aw?n ??k?? ati igb?? aye Jesu,o tun s? nipa igbe aye aw?n Krist?ni.

Maj??mu titun j?? apap?? aw?n iwe Krist?ni ti won ko ni ede Griki, ori?i aw?n eniyan mimo ni o ko aw?n iwe yii. Maj?mu titun ni ??p??l?p?? ij? j?? apap?? iwe metadinlogbon.

  • Aw?n iwe Ihin rere m??rin(Matiu, Maru, Luuku ati Johanu).
  • Iwe i?e aw?n Ap??siteli
  • Aw?n iwe m??tala Ap??siteli P????lu
  • Iwe si aw?n Heberu
  • 7 Aw?n iwe meje si aw?n Krist?ni
  • Iwe ifihan.

Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]


A?i?e it??kasi: <ref> tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/> tag was found