Ebute : Im?? i?iro

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
OJU EWE IMO ISIRO

Im?? I?iro j?? eyi t'on j? mo nipa ??p??iye (quantity), nipa opo (structure), nipa iyipada (change) ati nipa aaye (space). Idagbasoke imo Isiro wa nipa lilo afoyem???? (abstraction) ati ?gb??n ir??nu, pelu onka, isesiro, wiw??n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri (shapes) ati bi won se n gbera (motion). Eyi ni awon Onimo Isiro n gbeyewo, ero won ni lati wa aba tuntun, ki won o si fi oot?? re mul?? pelu itumo yekeyeke.

A n lo Imo Isiro ka kiri agbaye ni opolopo ona ninu Imo Sayensi , Imo Ise Ero , Imo Iwosan , ati Imo Oro Okowo . Bi a se n lo imo Isiro bo si apa eyi ti a n pe ni Iwulo Imo Isiro (Applied Mathematics). Apa keji Imo Isiro ni a mo si Imo Isiro Ogidi . Eyi je mo eko imo isiro to ko ti ni ilo kankan bo tileje pe o se se ki a wa ilo fun ni eyinwa ola.

Awon Orisirisi Nomba ti o wa
  • N??mba Ak??k??
  • N??mba Tod??gba
  • N??mba Tos??ku
  • N??mba Tikosi
  • N??mba Tosoro
  • N??mba Apaosi
  • N??mba Apa??tun
  • N??mba Adaba
  • N??mba Odidi
  • N??mba Oniipin
  • N??mba Alainiipin
  • N??mba Gidi
  • ' Awon Eka Imo Isiro'
    Eko Isiro Ipilese Imo Isiro Ero Nomba Imo Isiro Onijinle
    Agbeyewo Ninu Imo Isiro Aljebra Alawonile ati Ibamuile Imo Isiro Oniwulo