Ojuewe Ak??k??

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Adeniran Ogunsanya, amofin ati olo?elu ?m? oril??-ede Naijiria

Adeniran Ogunsanya QC , SAN (31 January 1918 ? 22 November 1996) j?? amofin ati olo?elu ?m? oril??-ede Naijiria , ti o si tun j?? ??kan pataki lara aw?n oludasil?? ?gb?? o?elu Ibadan Peoples Party (IPP) . O ?i??? g??g?? bi K?mi???na fun eto idaj?? ati eto ??k?? fun Ipinl?? Eko ni asiko i?ej?ba alagbada ?l??keji. Oun naa tun ni alaga pata pata fun ?gb?? o?elu Nigerian People's Party nigba aye r??. W??n bi Adeniran ni ?j?? K?kanlelogun o?u Kini ?dun 1918 ni agbegbe Ikorodu ni Ipinl?? Eko si agboole ?m? ?ba Suberu Ogunsanya Oguntade ti o j?? ?d??fin ti ilu Ikorodu nigba naa. Adeniran l? si ile-??k?? alak????b??r?? ti Hope Waddell Training Institute ni ilu Calabar nigba ti o ? gbe p??lu aburo baba r?? ti o j?? o?i??? ij?ba ni ilu Calaba. Ij?ba fi ??bun ??k??-??f?? da Adenira l??la lati kawe siwaju si ni ile-??k?? King's College ti o wa ni Ipinl?? Eko latari bi o ?e peregede jul? p??lu maaki ti o ga jul? ninu idanwo a?ekagba ti Standard VI (6) ni ?dun 1937. O t?? siwaju ninu ??k?? r??, ti o si k??k???? nipa im?? ofin ni ile-??k?? fasiti ti University of Manchester ati Gray's Inn ti o j?? ile-??k?? im?? ofin.

( it??siwaju... )

?j?? 10 O?u Karun :

Aw?n ?l??j??ibi looni...

Aw?n alaisi looni...

?j?? miran: 08 ? 09 ? 10 ? 11 ? 12 | iyoku...



? tun wo IroyinWiki ni ede G????si

T??mpili Dharmaraya Swamy, Bangalore , India .

Aw?n I???-?w?? Miran
Wikimedia Foundation ni o gba alejo Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awon ise-owo miran:
Wikiàyásọ Wikiayas?
Akoj? aw?n amus?
Wikiatúmọ̀èdè Wikiatum??ede
Atum??ede orisirisi ede
Wikispecies Wikispecies
Akoj? aw?n iru ??da
Wikiìròyìn Wikinews
Iroyin ??f??
Wikisource Wikisource
Aw?n ak?siiwe ??f??
Commons Wikimedia Commons
Aworan, iro ati fideo
Wikifásítì Wikifasiti
Elo ik????k?? ??f??
Wikiìwé Wikiiwe
Iwe??k?? ati iweawo?e ??f??
Meta-Wiki Meta-Wiki
Ibi akoso i???-?w?? Wikimedia
Wikidata Wikidata
Ibudo imo ??f??