Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Muhammadu Buhari
(ti w??n bi ni ?j?? ketadinlogun, O?u Kejila Odun 1942) olo?elu ti o j?? Aar? orile-ede
Naijiria
laarin ?dun 2015 si ?dun 2023.
[5]
[6]
O lo ?aa ak??k?? r?? laarin odun 2015 si 2019 ati keji laarin ?dun 2019 si 2023
[7]
. Buhari ti figba kan j?? ogagun Mej?? G??n??ra ati pe o j?e olori oril?? ede Naijiria lati 31st O?u kejila odun 1983 si O?u k?jo odun 1985, leyin ti o fi kuupu ologun gbaj?ba.
[8]
[9]
A bi Muhammadu Buhari si idile
Fulani
ni ?j? 17 Kejila 1942, ni Daura, Ipinle Katsina
[10]
, baba r? ni Hardo Adamu, ?ni ti o j?? olori Fulani, oruk? iya r?? si ni Zulaihat, ?ni ti o
Hausa
.
[11]
[12]
Oun ni ?m? k?talelogun baba r??. Iya Buhari ni o t? dagba, baba r?? fi aye sile nigba ti o wa ni ?m? ?dun m??rinrin
[13]
.
Buhari dara po mo
Nigerian Military Training College
(NMTC) ni ?dun 1962, o j?? omo odun kan dinlogun nigba naa.
[14]
Ni o?u keji ?dun 1964, a yi oruk? ile-iwe ologun naa pada si
Nigerian Defence Academy
(NDA).
Ni aarin 1962 si 1963, Buhari ko nipa imo ogun ni
Mons Officer Cadet School
ni ilu
Aldershot
,
England
.
[15]
Ni o?u kinni ?dun 1963, nigba ti Buhari j?? ?m? ?dun ogun, a s?? di
lieutenanti keji
.
|
---|
General
Olusegun Obasanjo
became head of state in
Nigeria
on 14 February 1976 after the assassination of General
Murtala Mohammed
. He replaced or re-assigned many of the state governors, and broke up some of the larger states into two or three new states. Obasanjo began the transition to democracy with the
Nigerian Second Republic
, allowing the election of governors who replaced the military appointees in October 1979.
|
|