Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Coordinates
:
29°34′24″N
2°22′23″E
/
29.5734571°N 2.3730469°E
/
29.5734571; 2.3730469
Algeria
(
Arabiki
:
???????
,
al-Gaz?’ir
), fun onibise
Oril??-ede Olominira O?elu aw?n Eniyan il?? Algeria
, je orile-ede ni
Ariwa Afrika
. Ile re ni ti orile-ede ti o tobijulo ni
Okun Mediterraneani
, ekeji totobijulo ni orile Afrika
[10]
leyin
Sudan
, ati ikokanla totobijulo lagbaye.
[11]
Algeria i bode ni ariwailaorun mo pelu
Tunisia
, ni ilaorun pelu
Libya
, ni iwoorun pelu
Moroko
, ni guusuiwoorun pelu
Apaiwoorun Sahara
,
Mauritania
, ati
Mali
, ni guusuilaorun pelu
Niger
, ati ni ariwa pelu Okun Mediterraneani Sea. Titobi re fe je 2,400,000 square kilometres (930,000 sq mi), be si ni iye awon eniyan re je 35,700,000 ni January 2010.
[12]
The capital of Algeria is
Algiers
.
Algeria je omo egbe
Iparapo awon Orile-ede
,
Isokan Afrika
, ati
OPEC
. Bakanna o tun kopa ninu dida ikoenu owo
Isokan Maghreb
.
A?i?e it??kasi:
<ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding
<references group="lower-alpha"/>
tag was found