Ilana · Aw?n Ibeere Wiw??p?? · Agbaj? · Aw?n ipinu ??na i?i??? Wikipedia · ?r? · WAP · Ibi I?oju (Embassy) · Ibapade
Adeniran Ogunsanya QC , SAN (31 January 1918 ? 22 November 1996) j?? amofin ati olo?elu ?m? oril??-ede Naijiria , ti o si tun j?? ??kan pataki lara aw?n oludasil?? ?gb?? o?elu Ibadan Peoples Party (IPP) . O ?i??? g??g?? bi K?mi???na fun eto idaj?? ati eto ??k?? fun Ipinl?? Eko ni asiko i?ej?ba alagbada ?l??keji. Oun naa tun ni alaga pata pata fun ?gb?? o?elu Nigerian People's Party nigba aye r??. W??n bi Adeniran ni ?j?? K?kanlelogun o?u Kini ?dun 1918 ni agbegbe Ikorodu ni Ipinl?? Eko si agboole ?m? ?ba Suberu Ogunsanya Oguntade ti o j?? ?d??fin ti ilu Ikorodu nigba naa. Adeniran l? si ile-??k?? alak????b??r?? ti Hope Waddell Training Institute ni ilu Calabar nigba ti o ? gbe p??lu aburo baba r?? ti o j?? o?i??? ij?ba ni ilu Calaba. Ij?ba fi ??bun ??k??-??f?? da Adenira l??la lati kawe siwaju si ni ile-??k?? King's College ti o wa ni Ipinl?? Eko latari bi o ?e peregede jul? p??lu maaki ti o ga jul? ninu idanwo a?ekagba ti Standard VI (6) ni ?dun 1937. O t?? siwaju ninu ??k?? r??, ti o si k??k???? nipa im?? ofin ni ile-??k?? fasiti ti University of Manchester ati Gray's Inn ti o j?? ile-??k?? im?? ofin.
( it??siwaju... )
F??to orun lati Solar Dynamics Observatory ti NASA .
Akiyesi! ? Ai?oju?aju · Ilana ay?ka kik? · ??t??awok? · Iwa tit?? · I?eey??wo · Ilana fun kik? l??ta Yoruba
Kik? ay?ka ? Kini Wikipedia j??? · Atun?e ojuewe · Afikun aworan · Ikopa · Tutorial · Apoti idanwo
Iranw?? Wikipedia ? Aw?n ojuewe tuntun · Aw?n ay?ka ??w??n · Aw?n ojuewe fun iyilededa · Aw?n ay?ka fun atun?e · I??r?
Nipa Wikipedia ? Ab?? igi · FAQ · Aw?n oni?e Wikipedia · Aw?n alamuojuto · Wikimedia · Software · Aw?n statistiki
Oruk?aye ? Wikipedia
Litire??? ? Ere-idaraya ? Filmu ? Orin ? Tiata ? I?eroyin ? T?lifisan ? Redio
I?????r? ? Internet ? Afigbebanis??r?? ? K??mputa
?bi ? Faaji ? Ofin ? ??r??-okowo ? Inawo ? I?elu ? ??r??-awuj? ? Eniyan ? ??k?? ? Imoye
Itoraw?? ? Ofurufu ? ??gbin ? Say??nsi k??mputa ? Fisiksi ? Iwosan ? Adanida ? K??mistri ? Bai??l??ji
Alj??bra ? Ituwo ? I?iro ? I?ed??gba ? J????m??tri ? N??mba ? T????r??mu ? ?gb??n
Aye ? Adagun ? Oril??-ede ? Okun ? Oril?? ? Ilu ? Afrika ? Asia ? Europe ? Guusu Am??rika ? Ariwa Am??rika
Ogun ? Oril??-ede t??l?? ? Il???baluaye ? ??r??-ayeij??un
Olori oril??-ede ? Oni???na ? O?ere ? Onim??say??nsi ? Amoye ? Olo?elu ? Oluk??we ? Oni?owo
??sin Yoruba ? Imale ? ??sin Kristi ? I?ebuddha ? I?ehindu
Imaralokun ? Idaraya ? Amaralokun ? it??ju ilera ? Arun ? ??r??-ajakal??arun
Aw?n Wikipedia ti w??n ni ju ay?ka 1 000 000 l?: Deutsch (j??mani) · English (g????si) · Francais (faranse)
Aw?n Wikipedia ti w??n ni ju ay?ka 500 000 l?: Espanol (spani) · Italiano · 日本語 (japones) · Nederlands (neerlandes) · Polski (polaco/polones) · Portugues (potogi) · Русский (r??sia)
Aw?n Wikipedia ti w??n ni ju ay?ka 100 000 l?: ??????? (arabe) · Български (bulgaro) · Catala (catalao) · 韓國語 (coreano) · 中文 (chines) · Dansk (dinamarques) · Slovencina (eslovaco) · Slovenščina (esloveno) · Esperanto · Suomi (finlandes) · עברית (hebraico) · Magyar (hungaro) · Bahasa Indonesia (indonesio) · Lietuviu (lituano) · Norsk (noruegues) · ????? (persa) · Roman? (romeno) · Српски / Srpski (servio) · Svenska (sueco) · ?eska (tcheco/checo) · Turkce (turco) · Укра?нська (ucraniano) · Ti?ng Vi?t (vietnamita) · Volapuk (volapuque) · Winaray