Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Gege bi
Weimar Olominira
(
Weimar Republic
) (
Weimarer Republik
(
iranw??
·
ikede
)
,
IPA:
[?va?ma?? ?epu?bliːk]
) ni awon
olukoitan
n pe orile-ede olominira onileasofin ti o je didasile ni 1919 ni
Jemani
lati dipo iru ijoba tobaluaye to wa tele, won soloruko fun
Weimar
, ilu ti
igbimo ilana-ibagbepo
ti pade. Sibesibe, oruko tonibise re si duro si
Deutsches Reich
(
Ile Obaluaye Jemani
;
German Empire
). Leyin
Ogun Agbaye Akoko
, ile olominira yi loyojade lati
Ijidide Jemani
ni November 1918. Ni 1919,
igbimo ile apapo
pade ni ilu Weimar, nibiti won ti ko
ilana-ibagbepo tuntun
fun Raik Jemani (German Reich), won gba ni 11 August. Iru
oseluaralu asolominira
kose nile ni ibere awon odun 1930, eyi samona fun igori aga
NSDAP
ati
Adolf Hitler
ni 1933. Botilejepe ilana-ibagbepo odun 1919 ko je fifagile fun tonibise, awon ofin ti ijoba Nazi se ni February ati March 1933, to je mimo bi
Gleichschaltung
("coordination") tumosi pe ijoba le sofin to tako ilana-ibagbepo. Ilana-ibagbepo ko niyi mo; bi be, odun 1933 ni won gba bi opin Weimar Olominira ati ibere "
Raik Keta
" ti Hitler.
Ni odun 14 ti Weimar Olominira fi wao koju opolopo awon isoro, ninu won ni
Owonpupo
, awon oloselu alaseju ati awon ologun oto won, ati ikorira latowo awon asegun Ogun Agbaye Akoko. Sibesibe, o bori awon ilana buburu
Iwe-ipinnu Versailles
, o se atunse
owonina
, seisodokan iselu owo-ode ati sistemu
onaojurin
.
- ↑
"Das Deutsche Reich im Uberblick"
.
Wahlen in der Weimarer Republik
. Retrieved
2007-04-26
.
- ↑
Cf.
Der Große Brockhaus: Handbuch des Wissens in zwanzig Banden
: 21 vols., completely revis. ed., Leipzig: F. A. Brockhaus,
15
1928-1935, volume 14 (1929): Vierter Band Chi?Dob, article: 'Deutsches Reich', pp. 611-704, here pp. 648 and 651. No ISBN.