Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Ipinle Delta
je ipinle kan nini awon
Ipinle
ni orile-ede
Naijiria
. Ipinle Delta wa ni apa Guusu
Naijiria
. Ada Ipinle Delta kale ni ojo ketadinlogbon, osu kejo, odun 1991(27, August 1991) ni abe isejoba Gen. Ibrahim Babangida
[1]
. Olu-ilu Ipinle Delta ni Asaba bi otile jepe ilu Warri ikan aje/oja kale si ju. Awon eya ti opoju ni Ipinle Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri
[2]
. Ipinle Delta ni Ijoba Agbegbe Ibile marundinlogbon(25)
[3]
Arakunrin Emmanuel Uduaaghan ti fi igba je gomina ipinle delta ri labe asia egbe oselu PDP. .Oruko gomina ipinle delta lowolowo bayii ni arakunrin Ifeanyi Okowa
? Aniocha North
? Aniocha South
? Bomadi
? Burutu
? Ethiope South
? Ethiope east
? Ika North East
? Ika South
? Isoko North
? Isoko South
? Ndokwa east
? Ndokwa west
? Okpe
? Oshimili North
? Oshimili South
? Patani
? Sapele
? Udu
? Ughelli North
? Ughelli South
? Ukwuani
? Uvwie
? Warri North
? Warri South
? Warri South West