한국   대만   중국   일본 
Oril??-ede olominira - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Oril??-ede olominira

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
(Atunjuwe lati Republic )
Aworan i?et??s??na.

Ijoba Olominira je iru ijoba eyi ti olori orile-ede ki se adobaje , tabi ?ba , ti awon eniyan ibe tabi ijoba ti won yan, si je alaselorile lati se akoso orile-ede bi won se fe lai toro ase lowo elomiran. Ni ede Geesi , republic wa la ti res publica ede Latini to tumosi ohun ode tabi ohun igboro .


Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]