Owonina

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
(Atunjuwe lati Currency )
Owo wewe

Owonina le je ohun ti won fi n se kara-kata ni awujo, ilu, ipinle tabi orile-ede kan fun apere naira Naijiria tabi owo wewe ati owo odidi owo ohun ti won je apa didimu ipese owo orile-ede kan. Apa keji ipese owo je awon ti won je fifipamo si ile-ifowopamo