Colin Luther Powell
ti won bi (?j??ibi 5 April, 1937 - O?u K?wa ?j? 18, ?dun 2021) j?? ?ni ay??si ?m? il??
Amerika
ati
??gagun
onirawo merin to ti feyinti kuro ni
Ile-ise Ologun Jagunjagun ile Amerika
. O tun je Alakoso Oro Okere ile Amerika lati 2001 - 2005 labe Aar?
George W. Bush
. Ohun ni ?ni
alawodudu
akoko ti yio gun ori ipo yi.
[1]
[2]
[3]
[4]
Nigbati wa ni ?nu ise ologun, Powell tun je Alabaagbim??p?? ??r?? Abo Oril??-ede ile Amerika (National Security Advisor, 1987-1989); Apese, Ile-ise Alase aw?n Ologun Jagunjagun ile Amerika (U.S. Army Forces Command, 1989); ati
Alaga Ijokopapo aw?n Oga ?m?-ologun ile Amerika
(Chairman, U.S. Joint Chiefs of Staff, 1989-1993), ori ipo yi lowa nigbati
Ogun Ikun Odo Persia
sele. Ohun ni o j?? ?ni alawodudu akoko, ati soso titi doni, ti yio kopa ninu
Ijokopapo aw?n Oga ?m?-ologun ile Amerika
(Joint Chiefs of Staff).
A bi Colin Luther Powell ni ?j?? 5 osu kerin odun 1937 ni Harlem to j? adugbo kan ni ilu
New York
fun Luther Theophilus Powell ati Maud Arial McKoy ti w?n ko wa sile lati ile
Jamaika
. O si dagba ni South Bronx. Apa aw?n obi re kan tun wa lati ile
Skotlandi
ati
Irelandi
. Powell lo si ile eko Morris High School to fi igba kan j? ti igboro ni Bronx, o pari nib?? ni 1954.
Powell darapo mo Reserve Officers' Training Corps ni ile eko City College ni New York o si salaye re leyin igba na g??g?? bi iriri ti o mu inu re dunjulo laye re, pe ohun ti ri ohun ti ohun f??ran ti ohun si m???? ?e, lokan re pe "ohun ti wa ara ohun ri." G??g?? bi Ked????ti, Powell darapo mo ?gb?? aw?n Ayinb?n Pershing ni City College. Nigbato pari eko re ni City College ni 1958, o gba ipo g??g?? bi igbak??ta ajagun ni
Ile-ise Ologun Jagunjagun ile Amerika
(second lieutenant, United States Army).
[5]
O?i?e ?m?-ogun lo j? fun odun 35, o di orisirisi Ile-ise apese ati ipo alaba?i?epo mu titi to fi gok?? de ipo Ogagun ni 1989.
[6]
- Igbak?ta Ajagun
(Second Lieutenant): June 9, 1958
- Igbakeji Ajagun
(First Lieutenant}: December 30, 1959
- Ajagun
Ile-ise Ologun Jagunjagun ile Amerika (Captain, U.S Army): June 2, 1962
- Agbaogun
(Major): May 24, 1966
- Igbakeji Akogun
(Lieutenant Colonel): July 9, 1970
- Akogun
(Colonel): February 1, 1976
- ??gagun ?l???????
(Brigadier General): June 1, 1979
- ??gagun Agbaogun
(Major General): August 1, 1983
- Igbakeji ??gagun
(Lieutenant General): March 26, 1986
- ??gagun
(General): April 4, 1989
Aw?n igbesoke
Okun
|
Ipo
|
?j???dun
|
|
?GG-GEN
|
1989
|
|
I?G-LTG
|
1986
|
|
?A-MG
|
1983
|
|
??-BG
|
1979
|
|
AKO-COL
|
1976
|
|
IAK-LTC
|
1970
|
|
AO-OMAJ
|
1966
|
|
AJA-CPT
|
1962
|
|
2AJA-1LT
|
1959
|
|
3AJA-2LT
|
1958
|
Alabaagbim??p?? ??r?? Abo Oril??-ede
[
atun?e
|
atun?e ami??r??
]
Nigbato di omo odun 49, Powell di Alabaagbim??p?? ??r?? Abo Oril??-ede fun Aare
Ronald Reagan
lati 1987 titi di 1989 lai fi ipo re sile g??g?? bi igbakeji ogagun (lieutenant general). Nigbato pari ise
Igbimo Oro Abo ile Amerika
, Powell gba igbesoke si ipo Ogagun labe Aare
George H.W. Bush
, o si ?i?e nigba die g??g?? bi Alas?, Ile-ise Apese aw?n Ologun Jagunjagun ile Amerika, to un mojuto gbogbo Ologun Jagunjagun, Ologun Jagunjagun Alagb??pamo, ati aw?n ?yo Ile-ise Ologun Olus?? ile Amerika (U.S. National Guard) fun orile Amerika, Alaska, Hawaii ati
Puerto Rico
.
Alaga Ijokopapo aw?n Oga Omo-ologun
[
atun?e
|
atun?e ami??r??
]
Afunse ise ologun to se gbeyin, lati October 1, 1989 titi di September 30, 1993 ni g??g?? bi Alaga ikejila
Ijokopapo aw?n Oga ?m?-ologun
, eyi ni ipo ologun togajulo ni
Ile-ise Alakoso Oro-abo ile Amerika
(U.S. Dept. of Defense).
Wikisource
has original text related to this article: