Althea Gibson

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Althea Gibson
Althea Gibson in 1956.
Oril??-ede USA  USA
Iga 1.80 m (5 ft 11 in)
?w?? igbayo tennis
?nikan
Iye idije 0?0
Grand Slam Singles results
Open Australia F (1957)
Open Fransi W (1956)
Wimbledon W (1957, 1958)
Open Am??rika W (1957, 1958)
?nimeji
Iye idije 0?0
Grand Slam Doubles results
Open Australia W (1957)
Open Fransi W (1956)
Wimbledon W (1956, 1957, 1958)
Open Am??rika W (1957)

Althea Gibson (August 25, 1927 ? September 28, 2003) je obinrin elere idaraya eni iye 1 lagbaye ara Amerika to je obinrin omo Afrika Amerika akoko to kopa ninu idije tenis lagbaye ati eni akoko to bori lati gba ife eye Grand Slam ni 1956. Won unpe nigba miran bi " Jackie Robinson ti tenis" nitoripe o mu opin wa si iwa " eleyameya ninu tenis."

Igbesiaye [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

A bi ni August 25, 1927 ni Silver , Clarendon County , South Carolina fun Daniel ati Annie Bell Gibson, Althea ni awon aburo meji, Daniel Jr. (to je mimi bi "Bubba"), ati Mildred ti se obinrin.



Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]