Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Tunde Alade?e
j?? oluk??tan ti o si tun ti gba ami-??y? ti
Africa Movie Academy Award for Best Actress in a Leading Role
ni ?dun 2018.
[1]
O ti k? itan ti
a 70 night drama
fun
MTV Shuga
filmed by the actors themselves over four countries, explaining and set during the
coronavirus lockdown
.
Alade?e ti nif?? si ere ori-itage lati igba ti o ti wa ni ile-??k?? alak????ber?? nibi ti o ti dara p?? m?? awuj? ?gb?? o?ere ti o si f??ran orin kik? p??llu. O k??k?? nim?? nipa ere-oni?e ninu ede
G????si
(English Literature) ni
Yunifasiti Ibadan
.
[2]
O tu k??o?? nipa ere ori-itage ni
Met Fi School
ni ilu
Lond??nu
,.
[2]
Alade?e ti k? itan fun
Edge of Paradise
ati
Tinsel
.
[3]
She was the head writer for the series
Hotel Majestic
.
[4]
Aj? [YNaija]] kaa m?? aw?n ?m? ogoji ?dun ti w??n ? kopa ribiribi ni oril??-ede
Naijiria
.
[5]
Ni ?dun 2018, ipa ti Alade?e ko ninu ere
The Lost Cafe'
g??g?? bi
Kenneth Gyang
ni w??n fi yan an fun
Africa Movie Academy Awards
g??g?? bi o?ere to peregede jul? .
[6]
Alade?e ma ? k? ere atigbadegba fun
MTV Shuga
, nigba ti w??n pe aw?n ?l??kan-o-j?kan ere ?uga ni
Shuga Down South
. O k? is??ri meji fun i??? naa ?aaju ki w??n to yan an g??g?? bi olootu agba fun i??? akan?e naa.
[7]
Ni asiko
ajakal?? arun Covid-19
, w??n ni ki o k? is??ri ere olojojum?? fun
MTV Shuga Alone Together
ki o si s? ipa ati idaamu ti arun Korona ? mu ba aw?n eniyan. W??n fi ere naa han ni ogunj?? o?u K?rin ?dun 2020.
[8]
W??n ?e ere naa ni oril??-ede
Naijiria
,
South Africa
ati
Cote D’Ivoire
.
[7]
The series was planned to last for 65 episodes.
[2]
Adak?:Authority control