Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Sunday Jack Akpan
(oruk? ibis? r? ni
Ikot Ide Etukudo
, 1940) j?? Agb??gi kere ti orile ede Naijiria ti won ? pe ni ede geesi ni "the contemporary African equivalent of the medieval artisan".
[1]
o j?? gbajumo fun i?e r??, i?e ere eyi ti o maa ? lo Sim??ti
cement
, eyi ti o maa ? fi ? gbe aw?n ere ibile fun aw?n ?ni Oye ati aw?n eeyan ja?ka?jaka?, ati aw?n oju iboju
grave art
, l??yin naa ni yoo wa kun ?da; ? ti ?e aw?n i?e ere lorisiriri, eyi ti o wa fun tita
commercial arts
, aw?n bi alufaa ij?sin ati aw?n eeyan ja?ka? ni awuj?.
[2]
aw?n i?e erele r?? wa ni ifihan ni
Venice Biennale
[1]
ati ni gbagede
Centre Pompidou
ni
Paris
, ati aw?n gbagede ifihan miiran.
[1]
aw?n i?e re naa ni
Horniman Museum
ni London.
[2]
Adak?:Authority control
Adak?:Nigeria-sculptor-stub