Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Saint Martin
(
Faranse
:
Saint-Martin
;
Duki
:
Sint Maarten
) je
erekusu
amooru ni ariwailaorun
Karibeani
, bi 300 km (186 miles) ilaorun orile-ede
Puerto Rico
. Erekusu yi to je 87 km
2
je pipin ni 60/40 larin
Fransi
(53 km
2
)
[1]
ati
Netherlands Antilles
(34 km
2
)
[2]
; ohun ni erekusu to kerejulo ti awon eniyan n gbe si
ninu okun ti o je pipin larin awon orile-ede meji
, eyi je be lati odun 1648.