한국   대만   중국   일본 
Saliu Adetunji - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Saliu Adetunji

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??

?ba Saliu Adetunji (ti a bi ni ?j?? k?rindinl??gb??n o?u k?j? ?dun 1928 - O?u K?ta ?j? 2, ?dun 2022) j?? ?ba alade loril?? ede Naijiria. Oun ni Olubadan ti ilu Ibadan l??w???l??w??. O gori it?? g??g?? bi Olubadan okanlelogoji l??j?? k?rin o?u k?ta ?dun 2016. [1] [2]

Itan aye r?? ni ib??r?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

W??n bi Kabiyesi Saliu Adetunji, Olubadan ti ilu Ibadan l??j?? k?rindinl??gb??n o?u k?j? ?dun 1928. Oruk? baba ati iya r?? ni Raji Olayiw?la ati Suwebatu Am??pe. I??? owo ori?iri?i ni ?ba Saliu k?? ni ib??r?? aye r?? ki o to wa faram?? i??? iran??, eyi lo mu un dero ilu Eko. L??yin i?e iran??, ?ba Saliu tun da i??? akahun-orin sil?? l??dun 1960. O pe ile i??? akahun-orin r?? ni Babalaje Records. I??? yii lo mu un gbajum?? debi pe oun lo ka ohun orin aw?n gbajugbaja aw?n olorin fuji bii; Dauda Epo-akara, King Wasiu Ayinde Marshal. Oun ni Balogun ilu Ibadan ki o to di Olubadan ti ilu Ibadan l??dun 2016. [3] [4]

Aw?n It??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. vanguard; vanguard (2016-03-04). "Adetunji crowned as 41st Olubadan of Ibadanland" . Vanguard News . Retrieved 2019-11-19 .  
  2. "Adetunji becomes the 41st Olubadan of Ibadanland" . Punch Newspapers ? The most widely read newspaper in Nigeria . 2015-12-15 . Retrieved 2019-11-19 .  
  3. "Tailor who would be next Olubadan - Nigeria and World News" . The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News . 2016-01-21 . Retrieved 2019-11-19 .  
  4. "Ibadan Chiefs Support Chief Saliu Adetunji As Next Olubadan" . Breaking Times . 2016-01-22. Archived from the original on 2016-06-12 . Retrieved 2019-11-19 .