Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Ryutaro Hashimoto
(橋本 龍太?
Hashimoto Ry?tar?
, ti a bi ni ?j?? k?kandinl??gb??n o?u keje ?dun 1937
[1]
ti o si ku ni ?j?? kiini o?u keje ?dun 2006) j?? olo?elu ?m? oril??-ede
Japan
to di
Alakooso Agba il?? Japan
lati ?j?? k?kanla o?u kiini ?dun 1996 titi di ?gb??n ?j?? o?u keje ?dun 1998. O j?? adari ??kan lara aw?n ?gb?? o?elu ti o lagbara ju l? ni oril??-ede naa ki o to di pe o k? i?elu sil??. Nitori itiju, ko kopa ninu idibo gbogboogbo ti oril??-ede Japan ni ?dun 2005. O ku ni ?j?? kiini o?u keje ?dun 2006 ni ile-iwosan kan ni ilu Tokyo.
[2]
[3]
|
---|
| | |
Italics
denote acting Prime Ministers
|