한국   대만   중국   일본 
Richard Akuson - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Richard Akuson

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Richard Akuson
Esq
Richard Akuson at The National Museum of African American History and Culture in Washington D.C..jpg
?j??ibi 26 O?u Keje 1993 ( 1993-07-26 ) (?m? ?dun 30)
Oril??-ede ?m? oril??-ede Naijiria
Ile??k?? giga Yunifasiti Ipinl?? Nasarawa, Keffi, ati ile-??k?? im?? ofin ti il?? Naijiria, Eko.
Gbajum?? fun LGBTQ+ activism
Title Founder and Editor of A Nasty Boy Magazine
Honours FORBES Africa 30 Under 30 (2019)
Website www.richardakuson.com

Richard Akuson (ti a bi ni ?j?? k?rindil??gb??n o?u keje ?dun 1993) j?? agb?j??ro ?m? oril??-ede Naijiria , aja fun ??t?? lori LGBTQ , o?k??we, olootu ati oludasil?? [1] iwe iroyin ti w??n ? pe A Nasty Boy, [2] eyi tii ?e iwe at??jade ak??k?? lori LGBTQ+ ni oril??-ede Naijiria . Ni ?dun 2019, Richard wa lara Forbes Afirika ?gb??n ti w??n daruk? lab?? ?gb??n [3] aw?n eniyan ti w??n duro gege bii olutako fun ayipada lati tako aw?n im?ran lile nipa ako, abo, ati Ibalop?? ni oril??-ede Naijiria nibiti Ibalop?? laarin ako p??lu ak? ati abo p??lu abo ti j?? ????? p?lu ??w??n ?dun m??rinla. Ni ?dun 2017, w??n yaan fun ami-??y? ti The Future Award Africa's, eyi tii ?e ami-??y? tuntun ti media. Richard tun j?? ?niti won ti yan ni eemeji ??t????t?? gege bii ?ni ti o dara jul? nipa iwe kik? lori fashion fun ami-??y? Abryanz Style and Fashion Award. L??hin ifil??l?? iwe irohin kan ti w??n ? pe ni Nasty Boya ni ?dun 2017, Richard wa lara aw?n ogoji ?m? il?? Naijiria ti o lagbara jul? ti o si wipe ?j?? ori I w?n ko i ti to ogoji ?dun ti Ynaija daruk?. [4]

Ib??r?? igbesi aye r? ati ??k??. [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

W??n bi Richard ni Akwanga, ni Ipinle Nasarawa , orile-ede Naijiria. Richard ni w??n bi ?e ikeji ninu aw?n ?m?kunrin m??ta, o dagba si idile ti w?n ko la ti w?n ko dara ?agbe. Baba r? j? olo?elu nigbati iya r? j? oluk?? ni k??l????ji. O l? si ile-iwe giga ti Shepherd's International, eyi ti o j?? lara ile-iwe aladaani ti aw?n onigbagb?? nibiti w??n ti ? pese ibugbe fun aw?n ?m? ile-iwe. L??hin eyi ni o l? si ile-eko giga Yunifasiti ti Ipinle Nasarawa ti o wa ni Kefi, fun im?? ??k?? ijinle ak??k?? ninu ofin. W??n pee si ile igbim?? ofin ti ile Naijiria gege bii onidaaj?? ati agb?j??ro ti ile a?ofin agba il?? Naijiria ni ?dun 2017, l??hin ti o ti k?? ??k?? gba oye ni ile-eko amofin ti ile Naijiria ti o wa ni Eko .

I??? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Akuson b??r?? i??? r? g??g?? bii oluk? ni ara nigbati o pe ?m? ?dun mejidinlogun. Ni ?dun 2014, o l??w?? p?lu ?e agbekal?? ILLUDED, eyi tii ?e p?p? pinpin f??to lori ??r? ayelujara. Ni ?dun 2016, w??n yan an si ipo lati ?e olori i ????ka fashion ati style ti BellaNaija. Ipo yi ni ipo ti o ?e ifil??l?? i??? ? r??. I??? ? r?? ni BellaNaija mu ki o gba ami ??y? ti Abryanz Style Fashion. W??n si tun yan an lati j?? o?k??we fashion ti o peregede jul? ni odun 2016. Lehin naa ni ?dun kanna ni Richard fi BellaNaija sil?? lati l? ?e ifil??l?? ?m?kunrin PR. Ni ?dun 2017, nigbati o wa ni ile-eko im?? ofin ti orile-ede Naijiria, ? ?e ifil??l?? A Nasty Boy, eyi to j?? titari aala [5] at??jade LGTBQ+ eyi ti o wipe laip?? ni o dagba ti o si ni okiki kariaye. [6]

Arok? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Ni o?u k?rin ?dun 2019 Richard ?e onigbagb? itan-ak?le kan fun ile-ise CNN ti o si s? aw?n oun ti o faa ti oun fi sa kuro ni orile-ede Naijiria wa si orile-ede Amerika fun aabo. Ni o?u keje ?dun 2019, o k? arok? ti o j?nil??kan [7] fun iwe iroyin New York Times, eyi ti o j? ti "atuny??wo ?j? Sunday" ti ak?le r? j?? "This is Quite Gay". Eleyii ni w??n ti jade gbangba ni oju abala akoko iwe iroyin Times ti ori ??r? ayelujara. Bakannaa ni o tun jade ninu iwe irohin ti w??n t?? jade loju ewe pataki ti ko farasin ni ?j?? Keji.

Akitiyan ati ibi aabo [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Richard wa ibi aabo l? si orile-ede Am??rika ni ?dun 2018 l??yin ti o sal? kuro ni orile-ede Naijiria l??yin ti o ti y? ninu ik?lu aw?n oniwa ibaj?? kan. Ni ilu Am??rika, o siwaju lati maa s??r?? ni gbangba nipa ik?lu ati a?a aibikita nipa ibalop?? ni oril??-ede Naijiria. O ti fi aaye sil?? fun if??r??wanil??nuwo p??lu aw?n OkayAfrica, Very Goog Light [8] ati The Black Youth Project, [9] nibiti o ti ?e alaye l??p??l?p?? aw?n oun ti o yi i???l?? buruku yii ka. Richard asiwaju lati maa j?? onigboya aja-fun-??t?? ?m? eniyan fun LGBTQ+ ati aw?n ti o wa ni agbegbe ibi aabo ni ilu Amerika.

Aw?n it??ka si. [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. Akinwotu, Emmanuel (2017-11-16). "Nigeria's Nasty Boy: 'People in my law class thought I worked for a porn site ' " . the Guardian . Retrieved 2021-09-14 .  
  2. "Get to know Nigeria’s most controversial fashion magazine" . Dazed . 2017-06-29 . Retrieved 2021-09-14 .  
  3. "Richard Akuson, Founder of A Nasty Boy, & Upile Chisala in Forbes Africa's 30 under 30 List for 2019" . Brittle Paper . 2019-07-05 . Retrieved 2021-09-14 .  
  4. Okafor, Chinedu (2018-01-03). "Amaka Osakwe, Richard Akuson, Tokyo James… See the #YNaijaPowerList2017 for Fashion and Beauty ≫ YNaija" . YNaija . Retrieved 2021-09-14 .  
  5. "A Nasty Boy: The Nigerian magazine breaking gender taboos" . BBC News . 2017-08-31 . Retrieved 2021-09-14 .  
  6. Idowu, Torera; CNN, for (2017-06-13). "Is this Nigeria's most controversial magazine?" . CNN . Retrieved 2021-09-14 .  
  7. "Opinion - ‘This Is Quite Gay!’" . The New York Times . 2019-07-06 . Retrieved 2021-09-14 .  
  8. "Crunching the numbers for coronavirus - Imperial College London" . Imperial News . 2020-03-13 . Retrieved 2021-09-14 .  
  9. "Richard Akuson: the 'A Nasty Boy' editor talks the future of his queer fashion magazine and life as an asylum seeker in the U.S." . The Black Youth Project . 2019-07-15 . Retrieved 2021-09-14 .