Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Oleta Adams
|
---|
|
Background information
|
---|
Oruk? abis?
| Oleta Angela Adams
|
---|
?j??ibi
| 4 O?u Karun 1953
(
1953-05-04
)
(?m? ?dun 71)
Seattle, Washington
, U.S.
|
---|
Iru orin
| Gospel
,
soul
[1]
|
---|
Occupation(s)
| Singer
|
---|
Instruments
| Vocals, piano
|
---|
Years active
| 1980?present
|
---|
Labels
| |
---|
Associated acts
| Tears for Fears, Mervyn Warren, Brooklyn Tabernacle Choir
|
---|
Website
| oletaadams.com
|
---|
Oleta Adams
(ojoibi May 4, 1953) j?? ak?rin ??mi ati ati at?duuru ara Am??rika to gbajum?? fun agbara ohun r??.
Adams ti won bi g??g?? bi ?m?binrin si ajihinrere, ti o si dagba si gbigb?? orin ??mi. Nigba ti o dagba, aw?n ?bi r?? kol? si Yakima, Washington. O b??r? orin kik? ni
s????si
.
Ki o to ri anfani lati k? orin r?, Adams foju wina ??p??l?p?? kik??sil??. Ni ?dun 1970s, o ko l? si
Los Angeles
, California, nibi ti o ti o se
r??k??du
.
P??lu am??ran oluk?? r?, Lee Farrell, o ko l? si Kansas City, Missouri, nibi ti o ti se aw?n ori?iri?i kik? orin ni ibi
ipejopo
.
Ni ?dun 1994, Adams f?? onilu ti oruko re nje John Cushon ni Methodist church ti o wa ni Kansas. W??n pade ni ?dun 1980 nigba ti won jo n se r??k??du fun Adams.
[2]