Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Eyi ni orin ti oril??-ede kan maa ? k? nigba ti w??n ba ? ?e ay?y?. W??n maa ? k? ?? ti olori oril??-ede miiran ba wa b?? w??n wo. W??n maa ? k? ?? nibi ti aw?n eniyan ba pe j? si tabi ibi o?elu to ba ?e pataki. ?nikan le da a k? fun gbogbo eniyan tabi ki gbogbo eniyan kopa ninu kik? r??.
??r?? inu orin yii maa ? yin oril??-ede ati aw?n eniyan ti o wa ninu r??. Orin yii maa n sabaa s? aw?n ohun ribiribi ti il?? kan ti gbe ?e.
Bouget de I’Isle
ni o k? orin ti il?? Faranse ni asiko ogun ni 1792.
Francis Scott Key
ni o k? ti il?? Am??rika ni 1814. A ko m? ?ni ti o k? ‘God save the Queen’ ti il?? G????si ?ugb??n 1745 ni w??n k??k?? k? ??. ‘
Arise, O Compatriots
’ ni o b??r?? orin oril??-ede
Naijiria
ti a ? lo l??w??l??w?? bayii.