Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Napoleon Bonaparte
[lower-alpha 1]
(15 August 1769 ? 5 May 1821) j?? olori ologun ati adari o?elu ati ?m? bibi ilu Corsica ni il??
Faranse
. O di ilu-m????ka ni asiko iyipada i?ej?ba ile
Faranse
, ti o si lewaju aw?n ijangbara ori?iri?i ni asiko
ogun
. G??g?? bi
Napoleon I
, oun ni
?ba il?? Faranse
lati ?dun 1804 si ?dun 1814, ati 1815. Napoleon ?e akoso ij?ba il?? Yuroopu ati agbaye fun bi ?dun m??wa, nigba ti o ? lewaju ninu aw?n ogun ori?iri?i ti a m?? si
Napoleonic Wars
. O ja ??p??l?p?? ogun, ti o si bori aw?n ogun ti o si mu lati gba aw?n ile l??p??l?p?? fun ij?ba Faranse, ti o si dari il?? Yuroopu lapap?? ?aaju ki ij?ba r?? to ?ubu ni ?dun 1815. O j?? ??kan lara aw?n adari ni oril?? agbaye ti w??n si ? k??k???? nipa i?ej?ba r?? jake-jado agbaye. O si wa ninu aw?n adari ti o gbayi jul? ni inu itan agbaye.
[2]
A?i?e it??kasi:
<ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding
<references group="lower-alpha"/>
tag was found