Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Micheline Anne-Marie Calmy-Rey
(ojoibi 8 July 1945) je oloselu ara
Switzerland
to di olori fun Eka Ijoba Apapo fun Oro Okere — eyun,
alakoso oro okere
orile-ede Switzerland. O tun je ikan ninu
Igbimo Ijoba Apapo Switzerland
lati 2002, ati Aare ni 2007.
Calmy-Rey je bibi ni
Sion
ni ibile
Valais
fun Charles ati Adeline Rey. Calmy-Rey gba iwe eri ni 1963 ni
St. Maurice
, ati iwe eri
DEA
ninu sayensi oloselu ni
Institut de hautes etudes internationales (HEI)
(Graduate Institute of International Studies) ni 1968. O wole oko ni 1966 ni gba to fe Andre Calmy. Won ni omo meji.
|
---|
1848 ? 1874
| | |
---|
1875 ? 1899
| |
---|
1900 ? 1924
| |
---|
1925 ? 1949
| |
---|
1950 ? 1974
| |
---|
1975 ? 1999
| |
---|
2000 ? doni
| |
---|