Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Babatunde Olatunji
|
---|
Oruk? abis?
| Michael Babatunde Olatunji
|
---|
?j??ibi
| (
1927-04-07
)
O?u K?rin 7, 1927
Ajido,
Lagos State
,
British Nigeria
|
---|
Alaisi
| April 6, 2003
(2003-04-06)
(?m? ?dun 75)
Salinas, California
|
---|
Iru orin
| Yoruba music
,
Apala
|
---|
Instruments
| Drums, percussion,
djembe
|
---|
Years active
| 1959?2003
|
---|
Labels
| Columbia
,
CBS
,
Narada
,
Virgin
,
EMI
,
Chesky
|
---|
Website
| olatunjimusic.com
|
---|
Michael Babatunde Olatunji
(April 7, 1927 ? April 6, 2003) oje onilu Naijiria, oluk?ni, alapon ninu awuj?, ati Olorin .
[1]
Olatunji j? ?m? bibi ilu Ajido, ni eba
Badagry
,
Lagos State
, ni guusu iw?-oorun
Nigeria
. ?kan lara
Ogu people
, a ?e afihan Olatunji si orin ibil?? ni afrika ni tete ?j? ori. Oruk? r? , Babatunde, tunm? si 'baba ti de', nitori a bi l?hin o?u Meji ti baba r?? ku, eni Ogu (
Egun
) ?kunrin, Zannu ku, a si pe Olatunji ni Babatunde
reincarnation
. Baba re je ap?ja father to f? j? oloye
chieftain
, iya re si je am?koko ti ? j? ?kan lara ?m?
Ogu people
. Olatunji lati ma so ede
Gun
(Ogu/Egun) ati
Yoruba language
. Iya iya r? ati iya iya r? - iya agba je alufa ti
Vodun
ati igbagb? Ogu,wo ma sin Vodun, bi Kori, ti ? j? ori?a ti ir?yin.
[2]
[3]
nitori iku baba r?? of his father's , ni tete ?j? ori a ko lati j? oye g?g? bi oloye .
Ni ?m? ?dun mejila, o m? pe ohun o fe di oloye. O ka iwe
Reader's Digest
iwe iroyin nipa
Rotary International
Foundation's scholarship program, ti ? si ko idanwo r? . A gba w?le ? l? si ile iwe giga United States of America ni ?dun 1950.
Olatunji gba Ebun iwe o f? ni ?dun 1950 o si ka iwe
Morehouse College
ni
Atlanta, Georgia
, nibiti o ni erongba, sugbon ko korin
Morehouse College Glee Club
. Olatunji je ?r? gidigidi si oludari Glee Club Dr. Wendell P. Whalum o so'wopo lati da egbe ak?rin choir's repertoire, "Betelehemu", orin keresimesi Naijiria . L?yin ti ? jade ni ile iwe Morehouse, o t?siwaju si
New York University
lati ka nipa public administration. Nibi ti ? ti b?r?, egbe onilu kekere lati ma pa owo bi ? ?e t?siwaju ninu iwe re .
[4]
- ↑
"The Nigerian drummer who set the beat for US civil rights"
.
BBC News
. 2020-09-01
. Retrieved
2020-09-05
.
- ↑
Olatunji, Babatunde; Atkinson, Robert (2005).
The Beat of My Drum: An Autobiography
.
ISBN
9781592133543
.
https://books.google.com/books?id=U6xiXqGm49IC&q=akinsola+akiwowo&pg=PA6
.
- ↑
Martin, Andrew R.; Matthew Mihalka Ph, D. (September 30, 2020).
Music around the World: A Global Encyclopedia [3 volumes]: A Global Encyclopedia
.
ISBN
9781610694995
.
https://books.google.com/books?id=wvb2DwAAQBAJ&q=zannu+olatunji&pg=PA625
.
- ↑
"Babatunde Olatunji 1927 ? 2003"
. African Music Encyclopedia. May 2003. Archived from
the original
on June 5, 2011
. Retrieved
June 6,
2011
.