Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Mercy Bank Abang
j?? oniroyin ni Naijiria.
[1]
O gba ??bun ninu iroyin ni ?dun 2017 lati ??d?? Hammarskjold Awards ni United Nations.
[2]
O ma ? ?e if??r??wanil??nur?? ti o pe ak?le r?? ni ??r?? p??lu Abang Mercy, o si ti gba aw?n alejo bii R?no Omokri, Dele Momodu ati Chude Jideonwo.
[3]
Ni ?dun 2017, o gba ??bun
Woman of the year
ni eka iroyin.
[4]
Ni ?dun 2012, o wa laarin aw?n obinrin ??d?? m??waa ti w?n ni ?j?? ??la didara.
[5]
O ?e oniroyin nigba idibo oril?? ede Ghana ni 2017.
[6]
O k? ori?iri?i iroyin nipa aw?n ikan ti aw?n olus? aguntan ti Fulani ? ?e ati bii w?n ?e pa aw?n eeyan ni agbegbe Gbagyi.
[7]
O b????r?? i??? lori telefisionu g??g?? bii oniroyin o?elu pelu Independent Television and Radio ni Abuja. O ti si ?e pelu aw?n ile i??? bii Oxfam GB Nigeria, West African Civil Society Forum, HeinrichBoell Foundation,EcoJournalism ati YNaija.
[8]
[9]
Ni igba ti o wa ni HeinrichBoell Foundation, o k? aw?n iroyin nipa bi agbegbe ayika aw?n ilu ni Naijiria ?e ri ati bi w?n ?e ma ri ni ?j?? ??la.
[10]
[11]
[12]
[13]
[14]
[15]
[16]
[17]
[18]
Ni ?dun 2014, w?n pe si ??r?? lori ij?ba, ??t?? eniyan ati ij?ba tiwa ? tiwa eyi ti African Union gbe kal?? ti aw?n eeyan lati oril??-ede ede ti o k?ja ogoji si wa nibe.
[19]
[20]
Ni o?u k?ta ?dun 2015, oun ati Kadaria Ahmed ti o j?? oniroyin fun BBC, j? ?e at?kun eto if??r??wanil??nur?? lori telefisionu fun Attahiru Jega ti o je alaga fun INEC.
[21]
O ?e if??r??wanil??nur?? ni o?u k?san-an ?dun 2014 fun igba keji adari t??l?? oril??-ede Naijiria, Atiku Abubakar.
Mercy j?? ?m? ?gb?? "Enough is Enough" ti Chude Jideonwo gbe kal??.
[22]
[23]
O pese iranl?w? fun eto LightupNigeria eyi ti Amara Nwankpa gbe kal?? lati ran aw?n ti w?n ?e aisan lara bii w?n ?e ? se wura ni Zamfara.
[24]