Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Leishmaniasis
tabi
leishmaniasis
je
arun kan
ti
protosan
o si ntan kaakiri ni ni kete ti awon kokoro kan ba bu ni j?.
kokoro
.
[1]
Kokoro na le farahan l?na m?ta pataki gegebi: kut?n?s, mukokut?n?s,tabi fisera l??maniasisi.
[1]
Kot?n?s na ma a nwa pelu ogbe awo-ara,nigbati mukokut?n?s ma a nwa pelu ?gb? awo-ara, enu, ati imu, ati wipe fisera ma a nb?r? pelu ?gb? aw?-ara, nigba to ba ya iba, awon s??li ?j? pupa di?, ?l? inu ati ?d? to tobi.
[1]
[2]
O le ni ogun orisiri
L??mania
ti o nse okunfa akoran arun yi lara eniyan.
[1]
Awon ohun to fa ewu ni: osi, airiounj?-j?, pipa igbo run, ati kikun-ilu.
[1]
Orisi m?t??ta lo se e y?wo labe ?r? mikroskopu.
[1]
Lafikun, arun fisera se e y?wo nipa ay?wo ?j?.
[2]
L??maniasisi se e daduro nipa sisun lab? aw?n ti o ni
oogun-?f?n
.
[1]
Awon igbes? miran ni fifi awon kokoro pelu oogun-efon ati titoju awon eniyan ti o ni arun yi lasiko ki o ma ba a tan kal?.
[1]
Iru itoju to ye se e m? nipa sise awari ibiti won ti ko arun na, awon iru
L??mania
, ati iru akoran.
[1]
Die lara awon oogun lilo fun arun fisera ni:
liposoma amfoterisin B
,
[3]
apap?
pentafalenti antimoniasi
ati
paromomisini
,
[3]
and
miltefosine
.
[4]
- ↑
1.0
1.1
1.2
1.3
1.4
1.5
1.6
1.7
1.8
"Iwe oro otito lori L??maniasisi. N°375"
.
World Health Organization
. January 2014
. Retrieved
17 February
2014
.
- ↑
2.0
2.1
Barrett, MP; Croft, SL (2012).
"Management of trypanosomiasis and leishmaniasis."
.
British medical bulletin
104
: 175?96.
doi
:
10.1093/bmb/lds031
.
PMC
3530408
.
PMID
23137768
. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3530408
.
- ↑
3.0
3.1
Sundar, S; Chakravarty, J (Jan 2013). "L??maniasisi: famakoterapi ti igbalode.".
Iro Amoye lori famakoterapi
14
(1): 53?63.
doi
:
10.1517/14656566.2013.755515
.
PMID
23256501
.
- ↑
Dorlo, TP; Balasegaram, M; Beijnen, JH; de Vries, PJ (Nov 2012). "Miltefosine: a review of its pharmacology and therapeutic efficacy in the treatment of leishmaniasis.".
The Journal of antimicrobial chemotherapy
67
(11): 2576?97.
doi
:
10.1093/jac/dks275
.
PMID
22833634
.