Kosta Rika

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Orile-ede Olominira ile Kosta Rika
Republic of Costa Rica

[ Republica de Costa Rica ] error: {{lang}}: text has italic markup ( help )
Motto:  "[ Vivan siempre el trabajo y la paz ] error: {{lang}}: text has italic markup ( help ) "    ( Spanish )
"Long live work and peace"
Orin iyin:  [ Noble patria, tu hermosa bandera ] error: {{lang}}: text has italic markup ( help )    (Spanish)
Noble homeland, your beautiful flag 1
Location of Kóstá Rikà
Oluilu
ati ilu totobijul?
San Jose
Aw?n ede i????ba Spani
Lilo regional languages Mekatelyu , Bribri
Oruk? araalu Kosta Rika
Ij?ba Oseluarailu onilana-igbepapo
( Orile-ede Olominira Oniaare )
Aar?
Rodrigo Chaves Robles
Stephan Brunner
Mary Munive
A?ofin Ileigbim?? A?ofin
Ilominira  
Filole
? latowo Spein
September 15, 1821
? latowo Meksiko
October 4, 1824
? latowo UPCA
March 21, 1847
? Recognized by Spain
May 10, 1850
Itobi
? Total
51,100 km 2 (19,700 sq mi) ( 128th )
? Omi (%)
0.7
Alabugbe
? July 2009 estimate
4,253,897 [1] ( 123rd )
? Idim??ra
85/km 2 (220.1/sq mi) ( 107th )
GDP   ( PPP ) 2009 estimate
? Total
$48.881 billion [2]
? Per capita
$10,579 [2]
GDP   (nominal) 2009 estimate
? Total
$29.318 billion [2]
? Per capita
$6,345 [2]
Gini   (2007) 48.0 [1]
Error: Invalid Gini value  ·  30th
HDI   (2007) 0.854
Error: Invalid HDI value  ·  54th
Owonina Costa Rican colon ( CRC )
Ibi akoko UTC -6 ( CTZ )
Oju??na ?k?? otun
Ami t?lifoonu +506
Internet TLD .cr

Kosta Rika (pipe /?ko?st? ?rik?/  ( listen ) ), lonibise o je Orile-ede Olominira ile Kosta Rika ( Spani : [ Costa Rica ] error: {{lang}}: text has italic markup ( help ) tabi Republica de Costa Rica , pronounced  [re?puβlika ðe ?kosta ?rika] ) je orile-ede ni Arin Amerika , o ni bode mo Nicaragua ni Ariwa, Panama ni ilaorun ati guusu, mo Okun Pasifik ni iwoorun ati guusu ati mo Omi-okun Karibeani ni ilaorun.

Kosta Rika, to tumosi "Eti Odo Olora", ti pa constitutionally ise ologun re re pelu ilana-ibagbepo ni 1949. [3] [4] [5] Ohun nikan ni orile-ede Amerika Latini to wa ni akojo awon orile-ede 22 oseluarailu pipejulo. [6] Kosta Rika lemolemo ti wa larin awon orile-ede Amerika Latini to gaju nipa Atoka Idagbasoke Eniyan , o si wa ni ipo 54th lagbaye ni odun 2007. [7] O wa ni ipo keta lagbaye, ati akoko ni gbogbo Amerika , nipa Atoka Bi Ayika Se Wa ni 2010. [8]

Ni 2007 ijoba Kosta Rikan sekede eto fun Kosta Rika lati di orile-ede ti ko lo karbon ni 2021. [9] [10] [11] Gege bi New Economics Foundation se so, Kosta Rika gba ipo kinni ninu Atoka Planeti Adunnu beesi ni o je orile-ede " alawoewe julo " lagbaye. [12]

Itan [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Ki Columbus o to wa ibe ri awon omo abinibi ile Kosta Rika je apa were part of the Agbegbe Arin kariaye to budo si awon agbegbe idasa Mesoamerika ati Andes . Eyi ti je siodotun lati kopo ipa agbegbe Isthmo-Colombian . Ibi yi ni awon asa abinibi Mesoamerika ati Guusu Amerika ti pade.

A pre-Columbian incense burner with a crocodile lid (500 ? 1350 AD), from Costa Rica.

Apa ariwaiwoorun orile-ede yi, Peninsula Nikoya , ni o je ibi guusujulo fun ipa asa Nahuatl nigbati awon olubori ara Spein de be ni orunddun kerindinlogun. Arin ati apaguusu orile-ede ni ipa Chibcha . Sibesibe, awon eniyan atilewa ti kopa lori asa Costa Rican odeoni niye to kere, nitoripe opolopo ninu won ku lowo awon arun bi smallpox [13] ati idamu latowo awon alamusin ara spein.



Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. 1.0 1.1 "Costa Rica" . CIA The World Factbook. Archived from the original on 2020-05-13 . Retrieved 2010-08-03 .  
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Costa Rica" . International Monetary Fund . Retrieved 2010-04-21 .  
  3. El Espiritu del 48. "Abolicion del Ejercito" (in Spanish) . Retrieved 2008-03-09 .  
  4. "Costa Rica" . World Desk Reference . Retrieved 2009-06-09 .  
  5. "Costa Rica" . Uppsala Universitet . Retrieved 2009-06-09 .   [ Ijap?? ti ko ?i??? m?? ]
  6. "Costa Rica's new president: Thriller for Chinchilla" . The Economist. 2010-02-11 . http://www.economist.com/world/americas/displaystory.cfm?story_id=15501885&fsrc=rss . Retrieved 2010-02-16 .  
  7. UNDP Human Development Report 2009. "Table H: Human development index 2007 and its components" (PDF) . UNDP . Retrieved 2009-10-05 .  
  8. Yale Center for Environmental Law & Policy / Center for International Earth Science Information Network at Columbia University. "2010 Environmental Performance Index" . Archived from the original on 2010-02-04 . Retrieved 2010-01-27 .  
  9. John Burnett (2008-02-18). "Costa Rica Aims to Be a Carbon-Neutral Nation" . National Public Radio (NPR.org) . http://www.npr.org/templates/story/story.php?storyId=19141333 . Retrieved 2009-04-27 .  
  10. Alana Herro (2007-03-12). "Costa Rica Aims to Become First "Carbon Neutral" Country" . Worldwatch Institute . http://www.worldwatch.org/node/4958 . Retrieved 2009-04-27 .  
  11. Alejandro Vargas (2007-02-21). "Pais quiere ser primera nacion con balance neutro de carbono" (in Spanish). La Nacion . Archived from the original on 2007-10-11 . https://web.archive.org/web/20071011010801/http://www.nacion.com/ln_ee/2007/febrero/21/aldea1002694.html . Retrieved 2009-04-27 .  
  12. Ashley Seager (2008-07-04). "Costa Rica is the world's happiest and greenest country in the world." . London: Guardian.co.uk . http://www.guardian.co.uk/environment/2009/jul/04/costa-rica-happy-planet-index . Retrieved 2009-07-04 .  
  13. "The Story Of... Smallpox" . Pbs.org . Retrieved 2010-06-26 .