Isiaka Adetunji Adeleke

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Isiaka Adetunji Adeleke
Governor - Osun State
In office
January 1992 ? November 1993
Asiwaju Leo Segun Ajiborisha
Ar??po Anthony Udofia
Senator - Osun West
L??w??l??w??
O gun ori aga
May 2007
Ar??po Mudasiru Oyetunde Hussein
Aw?n alaye onitohun
?j??ibi 15 January 1955
?gb?? olo?elu People's Democratic Party (PDP)
Profession Businessman, Politician

Isiaka Adetunji Adeleke (15 January 1955 ? 23 April 2017) j?? oloselu ati gomina ipinle Osun, orile-ede Naijiria , ti o si figbakan ri j? omo Ile Alagba Naijiria ti o soju ipinle Osun lemeji larin ?dun 2007 si 2011 lab? asia ?gb? o?elu People's Democratic Party (PDP) ti won si dibo yan l?kan si lab? asia ?gb?? All Progressives Congress in 2015. [1]

Igbesiaye [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Won bi Isiaka Adetunji Adeleke ni ?dun 1955 si idile Ayoola Adeleke ati Esther Adeleke. [2] . W?n bi ni [[ Ipinl?? ?nugu|ipinle Enugu]]. O b??r?? ile-??k?? alakobere ni Christ Church School, Enugu ki o to l?? si ilu Ibadan. [2] ?? pari ile-??k?? girama ni Ogbomoso Grammar School. [1] [3] [4]



Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. 1.0 1.1 "Sen. Isiaka Adetunji Adeleke" . National Assembly of Nigeria. Archived from the original on November 23, 2009 . Retrieved 2009-09-20 .  
  2. 2.0 2.1 Lawal, Olumide. "Isiaka Adeleke: 60 years of service to humanity" . sunnewsonline . Archived from the original on 5 January 2016 . Retrieved 27 December 2015 .  
  3. "Timi of Ede, Oba Oyewusi Agbonran II" . The Nation. 2009-08-22. Archived from the original on 2011-07-26 . Retrieved 2009-09-20 .  
  4. "Davido mourns late Uncle, Senator Isiaka Adeleke". The Vanguard. April 24, 2017.