Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Ipinl?? Ekiti
j??
Ipinle
ni apa iw?? oorun
Naijiria
ti o j?? didasil?? ni ?j?? kiini o?u ?wawa,
1996
p??lu aw?n ipinl?? tuntun marun-run miiran lat?w?? ??gagun
Sani Abacha
.
Ekiti ti j?? ipinl?? olominira ki aw?n oyinbo to de. Ekiti j?? ??kan ninu aw?n ipil?? Yoruba ni ibi ti a m?? si oril??-ede Naijiria ni oni. Aw?n ara
Ekiti
j?? aw?n ti a le t?pas?? w??n g??g?? bi ?m? Oduduwa, baba ati baba?la iran
Yoruba
.
[3]
Ero meji lowa nipa itan Ekiti. Ak??k?? ni eyi ti o so Ekiti m??
Ile-If??
. Itan naa s? pe ?l??fin, ??kan ninu aw?n ?m? Oduduwa ti o bi ?m? m??rindilogun. Nipa pe w??n ? wa il?? miiran lati gbe, w??n kuro ni Ile-If?? w??n si p?? soke raja. W??n gba Iwo- Eleru ni Isarun w??n si ni lati duro sibi kan ti oruk? r?? ?j?? Igbo-Aka ti ko jina si
Ile-Oluji
.
[4]
?l??fin ati aw?n ara r?? t??siwaju ninu irin-ajo w?n, ?ugb??n nigba ti w??n de il?? kan ti oruk? r?? ?j?? ?wa-Obokun (?ba il?? Ij??a) Orangun ti o j?? ?ba Ila pinnu lati duro si ibi ti a ? pe nih Ij???a ni oni ati
Igbomina
ni ipinl??
Osun
.
[5]
Aw?n ?m? m??rila yooku t??siwaju ninu irin aj?? w?n, w??n si gul?? si ibi ti a m?? si Ekiti ni oni. W??n ?e akiyesi pe oke p?? ni ibi ti w??n t??do si w??n si pe ib?? ni 'il?? olokiti' eyi ti o pada di Ekiti, bayii ni Ekiti ?e gba oruk?.
Adak?:Cn
Ero keji nipa orisun Ekiti ni pe Oduduwa to j?? baba?la iran Yoruba rin irin-ajo l? si Ile-If??, o ri pe aw?n kan ti t??do si ib??. Lara aw?n olori ti o ba nib?? ni Agbonniregun, Obatala, Orelure, Obameri, Elesije, Obamirin, Obalejugbe, ka m??nu ba di?? ninu w?n. Ohun ti itan s? nipe aw?n ar??m?d??m? Agb?nniregun ni w??n wa ni Ekiti, ap??r? ni Alara ati Ajero ti w??n j?? ?m? Ifa.
Orunmila
[Agbonniregun] gan-gan fun ra ?? gbe pup?? aye r?? ni Ado idi niyin ti w??n fi maa s?pe 'Ado ni ile-Ifa' . Atigba naa ni aw?n ara Ekiti tih wa nibi ti w??n wa di ??ni.
[6]
Ko si ?ni ti o le s? pato igba ti aw?n n?kan w??nyi ??l??, idi ni pe im?? m??-??-k?-m??-o-k?? o ti i de nigba naa, ohun kan ti o daju tadaa ni pe aw?n eeyan ti ? gbe ni Ekiti fun ??p?? ?dun. Itan j?? ki a m?? pe aw?n ?ba Ekiti ni ?la nigba aye w?n ni s???turi k?tala. Ap??r? ni Ewi Ata ti
Ado-Ekiti
ni ?dun
-
-
-
-
-
-
-
Arinta water fall
-
Arinta Waterfall
-
-
-
-
-
-
-
-
-
-
-
|
---|
This is a list of administrators and
governors of Ekiti State
.
Ekiti State
was created on October 1, 1996 from territory of
Ondo State
.
|