Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Ipinl?? Abia
(
Igbo
:
?ha Abia
) j?? ipinl?? kan ni agbegbe guusu-ila-oorun oril?? ede Naijiria, ti o pin aala si ariwa ati ariwa-ila-oorun p??lu aw?n Ipinl??
Enugu
, ati
Ebonyi
,
Imo State
si iw??-oorun, ipinl??
Cross River
si ila-oorun, ipinl??
Akwa Ibom
si guusu-ila-oorun, ati ni ipinl??
Rivers
si guusu. Ti w??n s? loruk? latara ib????r?? oruk? aw?n agbegbe m??rin ti o p?? jul? ni ipinl?? naa:
A
ba,
B
ende,
I
suikwuato, ati
A
rochukwu.
[3]
Olu-ilu r?? ni
Umuahia
ti agbegbe ti o gbooro jul? ti o si laju j??
Aba
.
[4]
Ipinl?? Abia j?? ipinl?? ?l????kejilel??gb??n ti o gbooro jul? ni aaye tabi agbegbe ati ?l????k?tadinl??gb??n ni iye p??lu eniyan ti o to mili??nnu m??rindinl??g??run-un-l??na-igbalel??g??rin g??g?? bi abajade ?dun 2016.
[5]
Lode-oni aw?n olugbe ipinl?? Abia lati bi ??p?? ?dun s??yin kunfun aw?n ori?iri?i ??ya, ?ugb??n aw?n
Igbo
ni w??n gbil?? ju ninu aw?n olugbe yii.
Ni ti eto ?r??-aje, i??? wiwa epo ati ohun alum??ni gaaasi ni o j?? gbooogi ni ipinl?? Abia p??l?? i??? agb??, nipataki i?u,
agbado
,
taro
,
epo pupa
, ati
paki
. Ile-i??? kekere kan ? ?agbejade, paapaa jul? ni agbegbe Aba.
[6]
Ti o si ? gberu kiakia ni iye ati ni Ile-i???, Abia ni isop??-?l????k??j? at??ka idagbasoke eniyan to ga jul? loril?? ede.
[7]
Aw?n Agbegbe Ij?ba Ibil??
(17):