Ibadan Peoples Party (IPP)

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??

?gb?? i?elu Ibadan Peoples Party (IPP) [1] ni aw?n laami-laaka ?m? bibi il?? Ibadan ti w??n tako bi nkan ?e ? l? ni apa ij?ba iw?? Oorun il?? Yoruba ?e ? l? si. W??n da ?gb?? i?elu yi sil?? ni ?dun 1950s. Aw?n ti w??n j?? ab?nugan inu ?gb?? naa ni Augustus Akinloye ti o j?? alaga, nigba ti ??p?? ninu aw?n ?m? ?gb?? naa j??: Adegoke Adelabu , Oloye Kola Balogun, Oloye T. O. S. Benson , Oloye Adeniran Ogunsanya ati H. O. Davies . Lara aw?n ti.w??n tun j?? agba-gba ninu ?gb?? naa ni: Oloye S. A. Akinyemi, Oloye S. O. Lanlehin, Oloye Moyo Aboderin, Oloye Samuel Lana, Oloye D. T. Akinbiyi, Oloye S. Ajunwon, Oloye S. Aderonmu, Oloye R. S. Baoku, Oloye Akin Allen ati Oloye Akinniyi Olunloyo.

Ipa ti ?gb?? i?elu naa ko ninu idibo ?dun 1951 [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Ni asiko idibo si ile igbim?? a?ofin ti apa il?? Yoruba ni apa Iw?? Oorun ti wa sopin ni ?dun 1951, o j?? ohun ti o ya pup???? ninu aw?n ?m? ?gb?? i?elu Action Group (AG) [2] l??nu wipe iye aw?n ?m? ?gb?? w?n ti w??n w?le sile a?ofin ko ju m??kandinl??gb??n (29) l? ninu aad??rin aye ti o ?ofo. Ba kan naa ni ?gb?? AG padanu pata pata ni ilu Ibadan ati ni ilu Eko ti o j?? ola ilu fun oril??-ede Naijiria nigba naa. Ero ?gb?? i?elu AG ni wipe aw?n yoo ni ibo to p?? jaburata nigba ti o j?? wipe aw?n ni ayo aw?n ?m? Yoruba; ??w??, ?gb?? i?elu IPP pese aw?n ?m? oye m??fa ni Ibadan, nigba ti 3gb?? i?elu NCNC ko gbogbo aye marun a to ku nile?? ni ilu Eko . Bi itan naa ?e l? ni wipe: ??gb??ni Harold Cooper, ti o j?? a?oju ij?ba nigba naa ni ki gbogbo ?gb?? k????kan o ?e ak?sil?? oruk? aw?n ?m? oye w?n ki o Ma baa si idaru-dap?? nibi eto idibo l??dun naa. ?gb?? Action Group nikan ni o t??le alakal?? yi, aw?n ?m? oye idije dupo lab?? ?gb?? i?elu w?n si ni: Obafemi Awolowo ati M.S. Sowole lati ?kun Ij??bu R??m?; S.O. Awokoya lati ?kun Ij??bu Ode, Rev. S.A. Banjo ati V.D. Phillips; Lati ?kun ??y?? - Chief Bode Thomas, Abiodun Akerele, A.B.P. Martins, T.A. Amao ati SB Eyitayo; lati ?kun ???un ? SL Akintola, JO Adigun, JO Oroge, S.I. Ogunwale, I.A. Adejare, J.A. Ogunmuyiwa ati S.O. Ola; Lati ?kun Ondo ? P.A. Ladapo ati G.A. Deko; ?kun Okitipupa ? Dr. L.B. Lebi, CA Tewe ati SO Tubo; lati ?kun ??p?? ? SL Edu, AB Gbajumo, Obafemi Ajayi ati C.A. Williams; lati ?kun Ik?ja - O. Akeredolu-Ale, SO Gbadamosi ati FO Okuntola; B?kun Agbadarigi ? Chief CD Akran, Akinyemi Amosu ati Rev. GM Fisher; Ekun ??gba ? J.F. Odunjo , Alhaji A.T. Ahmed, CPA Cole, Rev S.A. Daramola, Akintoye Tejuoso, SB Sobande, IO Delano ati A Adedamola. Lara w?n naa tun ni : ?kun ti ??gbado ? J.A.O. Odebiyi, D.A. Fafunmi, Adebiyi Adejumo, A. Akin Illo ati P.O. Otegbeye; ?kun If?? ? Rev S.A. Adeyefa, D.A. Ademiluyi, J.O. Opadina, ati S.O. Olagbaju; ?kun Ekiti ? E.A. Babalola, Rev. J Ade Ajayi, S.K. Familoni, S.A. Okeya ati D Atolagbe; ?kun ??w?? ? Michael Adekunle Ajasin , A.O. Ogedengbe, JA Agunloye, LO Omojola ati R.A. Olusa; ?kun Iw?? Oorun Ijaw ? Pere EH Sapre-Obi ati MF Agidee; lati ?kun Ishan ] ? Anthony Enahoro ; lati ?kun Urhobo ? WE Mowarin, J.B. Ohwinbiri ati JD Ifode; lati ?kun Warri ? Arthur Prest ati O. Otere, ati Kukuruku Division ? D.J.I. Igenuma. Lara aw?n adije-dupo ti a ka sil?? w??nyi, MA Ajasin lati ?kun ??w?? nikan ni o pinu lati ma dije m?? latari i???kan ?gb?? i?elu naa. O duro lati fun ak?gb?? r?? A.O Ogedengbe ati R.A Oluwa lati dije si ipo meji ninu m??ta ti o wa nil?? ni ile igbim?? a?ofin, nigba ti D.K. Olumifin b?? si ori aga ?y??kan ti o ku lab?? ?gb?? i?elu NCNC. Aw?n ?m? oye lab?? ?gb?? i?elu Action Group ti w??n si bori ni: Alhaji D.S. Adegbenro , ?kun ??gba; J.O. Osuntokun, ??kun Ekiti ati S.O. Hassan, lati ?kun ??p??.

Aw?n it??ka si [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. "WikiVisually.com" . WikiVisually . Retrieved 2021-05-29 .  
  2. "Action Group" . Encyclopedia Britannica . Retrieved 2021-05-29 .