Human Rights Watch

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Human Rights Watch
Iru Non-profit
NGO
Didasil?? ni 1978 under the name Helsinki Watch
Adopted current name in 1988. [1]
Ibujokoo New York City
O?i??? Kenneth Roth , Executive Director
Method Human rights , Activism
Ibitakun http://www.hrw.org

Human Rights Watch je agbajo aije ti ijoba kariaye kan to un sewadi ati akitiyan fun awon eto omoniyan . Ibujoko re wa ni ilu New York o si ni awon ibi-ise ni Berlin , Brussels , Chicago , Geneva , Johannesburg , London , Los Angeles , Moscow , Paris , San Francisco , Tokyo , Toronto , ati Washington D.C. [2]

Itan [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Oludari alase lowolowo fun Human Right Watch Kenneth Roth hun soro ni 44th Munich Security Conference 2008.

Human Rights Watch je didasile labe oruko Helsinki Watch ni odun 1978 lati mojuto bi orile-ede tele Isokan Sofieti se un tele Awon Ipinnu Helsinki .




Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. "Our History" . Human Rights Watch . Retrieved 2009-07-23 .  
  2. "Frequently Asked Questions" . Human Rights Watch . Retrieved 2009-07-23 .