한국   대만   중국   일본 
Gani Adams - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Gani Adams

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??

Faili:Aar? ??na Aar? ??na Kaka?fo

Gani Adams
?j??ibi Otunba Ganiyu Adams
30 O?u K?rin 1970 ( 1970-04-30 ) (?m? ?dun 54)
Arigidi-Akoko, Akoko North-West, Ondo State
Ile??k?? giga Lagos State University
I??? ajijangbara
Igba i??? 1992–present
Organization Olokun Festival Foundation
Movement Oodua Peoples Congress

Iba Ganiyu Adams t?i fi igba kan j?? olori ?gb?? ?m? Oduduwa ti aw?n eniyan m?? si O.P.C, A bi ??tunba Ganiyu Adam ni (?gb??n ?j?? o?u k?rin ?dun 1970). O j?? ajijangbara ati Aar? ??nakaka?fo. [1]

Igb?? aye r?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

W??n bi Gani Adams ni ?j?? k???d?gun o?u k?rin ?dun 1970, ni Arigidi-Akoko ti w??n pe ni Akoko North-west local government,Ondo State ni ode oni.

??k?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Gani Adams b??r?? ile-??k?? r?? ni Army Children's School, Otukpo, Ipinle Benue . Sugb??n nitori iru i??? baba r?, w??n ko l? si ilu Eko nibi ti o ti pari ile-??k?? alak??b?r?? ni Municipal Primary School ni Surulere ni Ipinl?? Eko ni ?dun 1980. L??yin ??k?? alak??b?r?? r??, o t?siwaju l? si Ansar-Ud-deen Secondary School, Randle Avenue, Surulere. L??yin ??k?? girama ,o l? k?? nipa ?i?e aw??n ????? ile ti o si pari ni ?dun 1987. [2]

Aw?n it??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. Odunsi, Wale (2018-01-16). "Aare Ona Kakanfo: Why I chose Gani Adams out of 25 candidates - Alaafin of Oyo" . Daily Post Nigeria . Retrieved 2018-07-20 .  
  2. "PROFILE: From OPC leader to generalissimo of Yorubaland, the transformation of Gani Adams" . TheCable (in Ede G????si). 2017-10-17 . Retrieved 2021-01-28 .