Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Fransi??m
tabi
Francium
, mimo tele bi
eka
-
caesium
ati
actinium
K
,
[akiyesi 1]
je
apilese kemika
to ni ami-idamo
Fr
ati
nomba atomu
87. O ni ikan ninu awon
odionina
tokerejulo larin gbogbo awon apilese ti a mo, bakanna ohun ni apilese aladanida
keji tosowonjulo
(leyin
astatine
). Fransiom je onide to je
radioalagbara
giga to n jera si astatine,
radium
, ati
radon
. Gege bi
onide alkali
, o ni
agbara elektroni
kan.
Francium je wiwari latowo
Marguerite Perey
ni
Fransi
(nibi ti apilese yi ti ri oruko) ni 1939. Ohun ni apilese togbeyin ti o je wiwari ninu
adanida
, kanran jije sisopapo.
[akiyesi 2]
Lode yara ise-idanwo, francium sowon gidigidi, iye ipase je wiwari ninu alumoni aladalu
uranium
ati
thorium
, nibi ti
isotopu
francium-223 ti n je didasile to si n je jijera bibaun. Iye to kere bi 20?30 g (ounce kan) lowa nigba yiowu kakiri inu
igbele
Aye
; awon isotopu yioku je alasopapo yanyan. Iye titobijulo ti o je kikojo lai isotopu yiowu ni isupo bi awon atomu 10,000 (ti francium-210) ti won je didasaye gege bi efuufu
tutugidi
ni
Stony Brook
ni 1997.
[1]
- ↑
Actually the least unstable isotope, francium-223
- ↑
Awon apilese alasopapo, bi
technetium
, ti je wiwari ninu adanida.