Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Fisay?? Aji??la
|
---|
?j??ibi
| Oluwafisay?? Ajib??la Aji??la
Ipinl?? Eko
,
Naijiria
|
---|
I???
| O?ere, Ak?rin, ati Model
|
---|
Igba i???
| 2011 ? present
|
---|
Website
| jef.org.ng
|
---|
Fisay?? Aji??la
, ti gbogbo eniyan tun m?? si
Freezon
,
[1]
j?? ?m? oril??-ede
Naijiria
ti o ?ere itage, model ati ak?rin. O di ilu m????ka latari ipa ti o ko ninu ere ?l??s????s??
Jenifa's Diary
, p??lu
Funk?? Akindele
. O tun ma ? kopa ninu ere ??l??s????s??
This Life
,
Nectar
,
Shadows
,
Burning Spear
,
Circle of Interest
ati
The Story of Us
ni ori ??r? amohu-maworan.
[2]
O k??k?? gboye ak??k?? ninu im??
Biochemistry
lati ile-??k?? Federal University of Agriculture,
Ab??okuta
(FUNAAB), ni
Ipinl?? Ogun
.
[1]
W??n bi Fisay?? ni Ilu Eko, am?? ?m? bibi
Ilu Ayedun
ni
Ipinl?? Ekiti
ni aw?n obi r??. oun si ni abik??yin aw?n ?m? m??tin ti aw?n obi r?? bi.
[3]
Fisay?? b??r?? ere-itage lati igba ti o ti wa ni ile-??k?? girama
Federal Government College (FGC) Odoogbolu
, ni
Ipinl?? Ogun
. O dara p?? m?? Ile-??k?? ik??ni ni ere itage ti
Wale Adenuga
( PEFTI School) ni inu o?e keje ?dun 2010, nibi ti o ti k?? nipa ere ori-itage.
[3]
Ere ti o k??k?? s??? di ilu m????ka ni
Nnena and Friends Show
, ninu o?e K?j? ?dun 2010.
[3]
O da aj? kan sil?? nigba ti o wa ni ile-??k?? Fasiti ti o pe ni
Jewel Empowerment Foundation
p??lu ero lati mu Idagba-soke ba aw?n ??d?? langba ati aw?n ogo w??r?.
[4]
O b??r?? i??? ere-itage ni p?r?u ni ?dun 2011, ti o si kopa ribiribi ninu aw?n ere ?l??s????s?? bi:
Tinsel
,
Burning Spear
ati
Circle of interest
. O sinmi di?? l??nu i??? fungba di?? lati le gbaju m?? ??k?? nigba ti o w?le si ile-??k?? Fasiti ni ?dun 2011. O b??r??.si ? gbe ere tir?? na .jade ni ?dun 2016, nigba ti o k??k?? gbe ere sinima bi
[1]
Road to Ruin
,
[5]
p??lu iranl??w?? aj9 r?? ti o da sil??. O gbe ere yi jade lati le ta ij?ba oril??-ede
Naijiria
ji ki e??n le ma pese i??? gidi fun aw?n ??d?? langba ti w??n k??k???? gboye imo ijinl?? gbogbo.
[3]
[6]
[5]
?dun
|
Akori ere
|
Ipa r??
|
Olugbere-jade ati Adari ere
|
Notes
|
2011
|
Tinsel
|
Co-star
|
Tope Oshin Ogun
|
Mnet TV series
|
2011
|
Burning Spear
|
Lead
|
Akin Akindele
|
TV Drama Series
|
2011
|
Circle of Interest
|
Co-star
|
Kalu Anya
|
TV Series
|
2012
|
Shadows
|
Lead
|
Tunde Olaoye
|
TV Series
|
2014
|
Nectar
|
Co-star
|
Sola Sobowale
|
TV Series
|
2015
|
This Life
|
Supporting Role
|
Wale Adenuga
|
TV Series
|
2016
|
Jenifa's Diary
|
Co-star
|
Funke Akindele
|
Sitcom
|
Adak?:Authority control