한국   대만   중국   일본 
O?elu - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

O?elu

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
(Atunjuwe lati Democracy )

O?elu je ijoba i?elu ara ilu boya to ba wa taara lati owo awon ara ilu tabi ki won fun awon asoju won lase ninu idiboyan lati lo agbara yi. Awon elede Geesi n pee ni democracy to wa lati inu ede Griiki : δημοκρατ?α - (d?mokratia) ti o tumo si "agbara aralu" [1] eyi ti won yi wa lati δ?μο? (demos) , "aralu" ati κρ?το? (kratos) "agbara" larin orundun ikarun-ikerin kJ lati toka si iru ilana oselu to wa nigba naa ni awon ilu orile-ede Grisi , pataki ni Ateni Atijo leyin rogbodiyan odun 508 kJ . [2]




Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. "Demokratia, Henry George Liddell, Robert Scott, "A Greek-English Lexicon", at Perseus" . Archived from the original on 2007-09-14 . Retrieved 2007-09-14 .  
  2. "democracy - History, Development, Systems, Theory, & Challenges" . Encyclopedia Britannica . 1992-12-07 . Retrieved 2018-11-07 .