Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Deborah Ajibola Abiodun
, ti ??p?? eniyan m?? si
"Kante,"
j?? ??kan lara aw?n agbab????lu oril??-ede
Naijiria
. ?j?? keji o?u k?kanla ?dun 2003 ni w??n bi, si ilu
Ibadan
, ni oril??-ede
Naijiria
.
[2]
If?? ti
Deborah
ni fun ere b????lu af?s??gba lati igba ewe r?? lo mu tay?? ninu ere naa.
[3]
O b??r?? irin-ajo i??? yii p??lu ?gb?? agbab????lu Rivers Angels lab?? asia ?gb?? aw?n agbab????lu-binrin ti oril??-ede Naijiria. Im?????e r?? lo mu gba eto ??k??-??f?? lati ?w?? ?gb?? agbab????lu fun aw?n obinrin ti University of Pittsburgh ni United States.
[4]
Im?????e Deborah lo mu ?i??? takuntakun g??g?? bi i Central Midfielder (CMF), Attacking Midfielder (AMF), Defensive Midfielder (DMF) ati agbab????lu to tay?.
[5]
Ni ?dun 2023, ni ?m?dun m??kandinlogun,
Deborah
kopa ninu FIFA Women's World Cup fun
Naijiria
, ni itako p??lu canada fun ipenija ti Ashley Lawrence.
[6]
Bi o til?? j?? pe ko si ?gb?? kankan to ju b????lu saw??n ninu ere naa, i??w?? gba b????lu r?? mu ki oju wa ni ara r??, titi w??n fi gba b????lu tan.
[1]