Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Deborah Kaye Allen
(ojoibi January 16, 1950) to gbajumo lasan bi
Debbie Allen
je osere, onijo, oluko-ijo, akorin-akowe-orin, oludari, olootu ara
Amerika
, ati omo egbe tele
President's Committee on the Arts and Humanities
.
[1]
[2]
Won ti pe loruko ni igba ogun fun
Ebun Emmy
(o gba ni emeta),
[3]
igba emeji fun
Ebun Tony
,
[4]
be ni o si gba
Ebun Golden Globe
ni ekan,
[5]
won si fun ni irawo ni ori
Hollywood Walk of Fame
ni 1991.
Allen gbajumo fun ere re lori ere orin-dirama telifisan
Fame
(1982-1987), nibi to ti sere bi Lydia Grant, olukoni-nijo, ohun si lo se oluko-ijo agba fun ere telifisan na. Fun isere yi ni 1983 o gba Ebun Golden Globe and Ebun Tony meji won si peloruko fun Ebun Emmy merin. Leyin na Allen sise bi oludari ati olootu, nibi to ti se olootu ati oludari ere osoose 83 ninu 144 fun ere komedi NBC
A Different World
(1988-1993). O pada si nisere ngba to kopa ninu ere telifisan NBC
In the House
lati 1995 di 1996, ati lati 2011 o bere sini sere bi Dr. Catherine Avery ninu ere dirama ile-iwosan ABC
Grey's Anatomy
nibi to tun ti sise bi olootu agba ati oludari.
[6]
O se oludari ere telifisan ati filmu to to 50.
Ni 2001, Allen si ile-eko ikojo Debbie Allen Dance Academy ni
Los Angeles, California
.
[7]
[8]
Ohun ni aburo
Phylicia Rashad
ti ohun na je akorin, osere ati oludari.
- ↑
"Current Members"
. President's Committee on the Arts and the Humanities. Archived from
the original
on January 16, 2005
. Retrieved
August 13,
2008
.
- ↑
"Debbie Allen, Culver City, California"
. President's Committee on the Arts and the Humanities. 2008. Archived from
the original
on January 17, 2009
. Retrieved
August 13,
2008
.
- ↑
"Debbie Allen"
.
Television Academy
.
- ↑
A?i?e it??kasi: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named
tonyaw
- ↑
"Debbie Allen"
.
www.goldenglobes.com
.
- ↑
Andreeva, Nellie; Andreeva, Nellie (May 6, 2015).
"Debbie Allen To Serve As Executive Producer/Director On ‘Grey’s Anatomy’"
.
- ↑
Gibson, Cynthia (2016-02-19).
"Black History Profile: Debbie Allen, ‘Born To Dance’"
.
Los Angeles Wave
(in Ede G????si). Archived from
the original
on 2016-09-07
. Retrieved
2020-01-16
.
- ↑
de Luna, Marcy (2019-01-15).
"Houston-born actress and choreographer Debbie Allen turns 69"
.
Houston Chronicle
. Retrieved
2020-01-16
.