한국   대만   중국   일본 
Dapo Abiodun - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Dapo Abiodun

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Dapo Abiodun
Gomina Ipinle Ogun
L??w??l??w??
O gun ori aga
29 May 2019
Asiwaju Ibikunle Amosun
Aw?n alaye onitohun
?j??ibi 29 O?u Karun 1960 ( 1960-05-29 ) (?m? ?dun 64)
Iperu Remo , Ogun State , Nigeria
?gb?? olo?elu All Progressives Congress (APC)

Dapo Abiodun (ti w??n bi ni ?j?? k?kandinl??gb??n o?u Karun-un ?dun 1960) j?? oni?owo ati olo?elu ?m? il?? Yoruba lati ipinl?? Ogun loril??-ede Naijiria . O j?? Gomina Ipinl?? Ogun nigbati O bori idibo ti Gomina ni ?dun 2019 lab?? asiya ?gb??-o?elu (APC). [1] Dap?? Abi??dun ni olori igbim?? ti Corporate Affairs Commission. [2] O tun j?? alakoso ati oludari ti ile epo Heyden ati oludasil?? First Power Limited. Ni ?j?? kewa o?u k?ta ?dun 2019, igbinm?? ti o n dari idibo ni il?? Naijiria eyi ti o j?? Independent Electoral Commission kede Dapo Abiodun g??g?? bi Gomina ti a dibo yan ni Ipinl?? Ogun . W??n ?e ibura fun un g??g?? bi Gomina Ipinl?? Ogun ni ?j?? k?nkandinl??gb??n, o?u karun-un, ?dun 2019 (29 may 2019)

Igba Ewe [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Dap? Abi?dun wa lati Iperu Rem? ni Ipinl?? Ogun . O wa lati idile ?ba. A bi sinu ?bi d??kita Emmanuel ati Arabinrin Victoria Abiodun ti w??n wa lati Iperu Rem? ni ila-orun Ipinl?? Ogun ni ?j?? k?kandinl??gb??n o?u karun ?dun 1960 (29 May 1960).

??k?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Dap? Abi?dun k?? ??k?? nipa im?? ??r? ni ile ??k?? giga Fasiti Obaf??mi Awol??w?? ti o wa ni

I??? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Dap? Abi?dun ni alakoso ati oludari ile i??? Heyden Petroleum Limited (UPL), ile i??? ti epo ati gaasi ni il?? Naijiria . O tun j?? oludasil?? ile i??? First Power Limited.

O?elu [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Dap? Abi?dun j?? ??kan lara ?m? ?gb?? ti O da ?gb?? Alaburada (Peoples Democratic Party) sil?? ni Ipinl?? Ogun, biotil??j??pe O j?? ??kan lara ?m? ?gb?? onigbal? ( All Progressive Congress ) l??w??l??w?? bayi nigbati O fi ?gb?? ti O wa t??l?? sil?? l?hin idibo gbogboogbo ti ?dun 2015. O dije du ipo lati l? si ile igbim?? a?ofin agba lati l? ?oju ila oorun ti Ipinl?? Ogun lab?? ?gb?? onigbale ( All Progressive Congress ) ninu idibo gbogboogbo ti o waye ni Naijiria ni ?dun 2015 eyi ti O padanu r? fun ?m? ?gb?? Alaburada ( Peoples Democratic Party ). W??n yan Dap? Abi?dun g??g?? bi ??kan lara aw?n a?ofin agba ti ij?ba apap?? il?? Naijiria ni ?dun 1988 lab?? ?gb?? United Nigeria Congress Party (UNCP) eyi ti o ti kogba si ile. O ti ?i??? sin lab?? igbim?? aar? ati ile i??? lorisirisi. [3]

Ni ?dun 2019, O dije ninu idibo ti Gomina ni Ipinl?? Ogun lab? ?gb?? onigbale ( All Progressive Congress ). O si bori ibo na. [4] O j?? ?m? l??hin kristi tooto ti O si nj?sin p??lu ile ij?sin (Mountain Of Fire And Miracles Ministry). O ti j?ri pe p??lu gbogbo bi atako lati ma le de ofisi ti Gomina Ipinl?? Ogun ?e p?? to, Olorun si tun mu O un de ib??.

Igbesi Aye Ara R?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Abiodun ?e igbeyawo si Bamidele Abiodun l??dun 1990, o si bi ?m? marun-un, lara r?? ni oloogbe Olugbenga Abiodun, DJ Naijiria kan ti a tun m?? si DJ Olu. [5] [6]

Aw?n it??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. Lawal, Nurudeen (2018-10-16). "11 facts you should know about Dapo Abiodun, Ogun APC governorship candidate" . Legit.ng - Nigeria news . Retrieved 2019-09-23 .  
  2. "Why I want to succeed Amosun in 2019- Dapo Abiodun" . Vanguard News . 2018-08-18 . Retrieved 2020-02-06 .  
  3. Lawal, Nurudeen (2018-10-16). "11 facts you should know about Dapo Abiodun, Ogun APC governorship candidate" . Legit.ng - Nigeria news . Retrieved 2020-02-06 .  
  4. Published (2015-12-15). "If you are humble, you can overcome any mountain, says Ogun governor-elect, Dapo Abiodun" . Punch Newspapers . Retrieved 2020-02-06 .  
  5. "Father Of DJ Olu, Mourns Late Son" . Sahara Reporters . 2017-10-14 . Retrieved 2020-01-10 .  
  6. "PROFILE: Dapo Abiodun, Governor of Ogun State, Nigeria [2019 --] | Premium Times Nigeria" (in Ede G????si). 2021-01-24 . Retrieved 2022-03-09 .