Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Chris Brown
|
---|
Brown performing at
Supafest
Australia, April 2012.
|
Background information
|
---|
Oruk? abis?
| Christopher Maurice Brown
|
---|
?j??ibi
| 5 O?u Karun 1989
(
1989-05-05
)
(?m? ?dun 35)
|
---|
Ib??r??
| Tappahannock
,
Virginia
, U.S.
|
---|
Iru orin
| R&B
,
pop
,
hip hop
,
dance
|
---|
Occupation(s)
| Singer, songwriter, rapper, dancer, actor
|
---|
Years active
| 2004?present
|
---|
Labels
| Jive
,
Zomba
,
RCA
|
---|
Associated acts
| Big Sean
,
Bow Wow
,
Game
,
Juelz Santana
,
Kevin McCall
,
Lil Wayne
,
Rihanna
,
T-Pain
,
Tyga
|
---|
Website
| chrisbrownworld.com
|
---|
Christopher Maurice
"
Chris
"
Brown
(ojoibi May 5, 1989) je
olorin
,
onijo
, ati
osere
ara Amerika. A bi ni
Tappahannock, Virginia
, o seko ara re lati mo orin ko ati ijo nigba to wa lomode be sini o tun je omo egbe akorin soosi. Ni gba to se adehun pelu
Jive Records
ni 2004, Brown gbe awo akoko to ni
akole oruko re
jade lodun to tele. O de ipo keji lori
Billboard
200
ni Amerika be sini o gba
iwe-eleri
platinomu eleemeji latowo
Recording Industry Association of America
(RIAA) laipe. Pelu orin single akoko "
Run It!
" to de ipo kini lori
Billboard
Hot 100
ni Amerika, Brown di okunrin olorin akoko leyin
Diddy
ni 1997 to gbe awo jade nipo kinni lori chart Amerika. Awo re keji
Exclusive
(2007) na tun gbe orin single ipo kinni jade "
Kiss Kiss
", ati "
With You
" ati "
Forever
". Awo yi na gba iwe-eleri platinomu eleemeji latowo RIAA.