Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Bim?b?? Akint??la
|
---|
|
?j??ibi
| 5 O?u Karun 1970
(
1970-05-05
)
(?m? ?dun 54)
Ibadan
|
---|
Oril??-ede
| Nigerian
|
---|
Ile??k?? giga
| University of Ibadan
(B.A)
|
---|
I???
| Actress
|
---|
Igba i???
| 1995?present
|
---|
Bimb?? Akint??la
(ti w??n bi ni ?j?? Karun-un, o?u karun-un ?dun 1970) j?? o?erebinrin sinima agbelewo ?m? oril??-ede Naijiria.
[1]
[2]
[3]
[4]
Won bi Akintola ni ojo Karun un osu karun-un odun 1970
[5]
baba re je omo bibi ipinle
Oyo
ti iya re si je omo bibi Ipinl??
Edo
. O lo si ile-iwe alakobere ti awon Ijo Aguda ti o wa ni ni agbegbe
Maryland
ni
Ipinl?? Eko
. Leyin eyi, o tesiwaju lo si ile eko girama ti awon ologun ti o wa ni
ipinle Eko
. O k'eko gboye imo nipa ere ori itage lati ile eko giga Yunifasiti ti
Ibadan
.
[6]
[7]
Ise akoko ti o gbe jade ni eyi ti o se ninu fiimu OWO BLOW ni odun 1995, eleyi ti oun ati Femi Adebayo jo se ati eyi ti o tun se leyin re ti a n pe ni
Out of Bounds
ni odun 1997
[8]
ti o se pelu Richard Mofe Damijo. Awon onworan fiimu so wipe oun ni o mo ere itage se ju ni odun 2013 nigba ti won wo ipa ti o ko ninu fiimu ni odun 2013 ninu eto ti a ti n mo riri awon elere ori itage ni orile ede Naijiria.
- Owo Blow
(?dun 1995)
- Out of Bounds
(?dun 1997)
- The Gardner
(?dun 1998)
- Dangerous Twins
(?dun 2004)
- Beyond the Verdict
(?dun 2007)
- Smoke and Mirrors
(?dun 2008)
- Hoodrush
(?dun 2012)
- AyItale
(?dun 2013)
- Heaven's Hell
(?dun 2015)
- 93 Days
(?dun 2016)
- ↑
"Bimbo Akintola, Toyin Oshinaike in troubled union". punchng.com. Archived from the original
on 14 August 2014.
- ↑
"Bim?b?? Akint??la, Falode canvass support for working mothers"
. punchng.com. Archived from
the original
on 14 August 2014
. Retrieved
13 August
2014
.
- ↑
"Age is no barrier to marriage ? Bimbo Akintola"
. punchng.com. Archived from
the original
on 14 August 2014
. Retrieved
13 August
2014
.
- ↑
"Bimbo Akintola cries out: I don’t need a husband!"
. vanguardngr.com
. Retrieved
13 August
2014
.
- ↑
"30 Nigerian entertainers presently in the league of 40s"
. December 9, 2015
.
http://thenet.ng/2015/12/special-report-30-nigerian-entertainers-presently-in-the-league-of-40s/
.
- ↑
"Bimbo Akintola Biography"
. gistus.com
. Retrieved
13 August
2014
.
- ↑
"Why I Am Not Yet Married At 42..Bimbo Akintola"
. cknnigeria.com
. Retrieved
13 August
2014
.
- ↑
"Out of Bounds"
.
Internet Movie Database
. Retrieved
25 October
2014
.