한국   대만   중국   일본 
Atiku Abubakar - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Atiku Abubakar

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Atiku Abubakar
11th Vice President of Nigeria
In office
O?u Karun 29, 1999 ? O?u Karun 29, 2007
Aar? Olusegun Obasanjo
Asiwaju Mike Akhigbe
Ar??po Goodluck Jonathan
Aw?n alaye onitohun
?j??ibi 25 O?u K?kanla 1946 ( 1946-11-25 ) (?m? ?dun 77)
Adamawa State , Nigeria
?gb?? olo?elu Peoples Democratic Party

Atiku Abubakar GCON (ti w??n bi ni ?j?? k?????d??gb??n o?u k?kanla ?dun 1946) j?? gbajugbaja olo?elu ?m? bibi ipinl?? Adamawa loril?? ede Naijiria . Oun ni Igbakeji Aar? oril?? ede Naijiria nigba i?ej?ba Aar? Olu???gun ?basanj?? lati ?dun 1999 si ?dun 2007. [1] [2] L??dun 2019, o dije dupo Aar? oril?? ede Naijiria lab?? asiya ?gb?? o?elu Peoples Democratic Party tako Aar? Muhammadu Buhari ti ?gb?? o?elu All Progressives Congress , ?ugb??n ibo ati ori ko ?e e loore, o fidi remi. [3]

Ni osu kaarun odun 2022,ni won yan Atiku Abubakar gege bi oludije fun aare oril?? ede Naijiria ti odun 2023 lab?? asiya ?gb?? o?elu Peoples Democratic Party . [4] [5] [6]

Lati igba ti o ti wo oselu ni 1989, Atiku Abubakar ti dije fun ipo aare orile-ede Naijiria ni emarun(odun 1993, 2007, 2011, 2015 ati 2019) ti o si fidiremi. Ni odun 1993, o fidiremi ni idibo primari fun Moshood Abiola ati Baba Gana Kanibe. [7]

Idile r?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

A bi Abubakar ni 25 November 1946 si ilu J??daa, Ipinl?? Adamawa . [8] Oruk? baba r?? ni Garba Abubakar, ?ni ti o j?? o?taja ati agb?? Fulani , oruk? Iya Atiku si ni Aisha Kande. A s? Atiku Abubakar loruk? Baba-agba r??, ?ni ti o ? j?? Atiku Abdulqadir, o si j?? ?m?bibi ilu Wurno, ipinle Sokoto , ko to dipe o l? si ilu J??da.

Eko re [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Baba Atiku Abubakar lodi si eko, o si gbiyanju lati mo je ki Atiku kawe sugbon ni igba ijoba gbo nipa oro yii, won ti baba Atiku mon ewon fun ojo die ki o to dipe iya-iyawo re san owo lati gba lee. Atiku Abubakar bere iwe nigbanigba ti o je omo odun mejo.

Abubakar lo ile iwe Jada Primary School ni ipinle Adamawa. Leyin igba ti o pari eko re ni odun 1960, o wole si ile eko Sekondiri ti Adamawa ni odun kana, pelu omo ile-iwe okandinlogota(59) bi ti re. Ni odun 1965, o keko jade ni ile-iwe naa, o si ni "grade three ni idanwo abajade WAEC re. [9] Leyin iwe sekondiri, Abubakar tesiwaju iwe ni Nigeria Police College ni Kaduna, sugbon o kuro leyin igba die nitori ko fi eri esi idanwo Mathematics re han. Leyin naa, o sise agbowo ode koto dipe o wole si ile-iwe School of Hygiene ni Ipinle Kano ni 1966, o ko eko jade pelu ami-eye Diploma ni odun 1967. [10] Atiku tun tesiwaju iwe leyin eyi.

Idile re [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Atiku ni iyawo merin ati omo mejidinlogbon. [11] Atiku so wipe: "Mo fe ni idile ti o tobi, mo wa ni eminikan lopolopo nigba ti mo wa lomode, mi o ni egbon tabi aburo okunrin tabi obinrin. Mi o fe ki awon omo mi wa ni awon nikan bi o ti je nigba ti mo wa lomode, oun ni mo se fe ju iyawo kan lo, an iyawo mi je aburobinrin mi, ore mi ati olubadamoran mi, won si un ran arawon lowo.

Ni odun 1971, Atiku fe Titilayo Albert ni ikoko, ni ilu eko, o fe ni ikoko nitoripe idile re koko tako ife won. [12]


Aw?n It??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. "Atiku Abubakar - Profile" . Africa Confidential . 2019-12-19 . Retrieved 2019-12-19 .  
  2. "The Nigerian operator who knows how to make money" . BBC News . 2019-02-06 . Retrieved 2019-12-19 .  
  3. Lawal, Nurudeen (May 30, 2022). "APC rigged 2019 presidential poll results, stole my votes in 5 states - Atiku" . Legit.ng - Nigeria news . Retrieved June 9, 2022 .  
  4. "A Vice President for Atiku" . THISDAYLIVE . June 10, 2022 . Retrieved June 11, 2022 .  
  5. "Running mate: Crisis looms as Atiku intensifies consultations" . Vanguard News . June 10, 2022 . Retrieved June 11, 2022 .  
  6. Daramola, Kunle (June 10, 2022). "2023: Tinubu will defeat Atiku in Adamawa, says Babachir Lawal" . TheCable . Retrieved June 11, 2022 .  
  7. "Atiku’s Many Shots at Presidency ? THISDAYLIVE" . THISDAYLIVE ? Truth and Reason . 2018-10-08 . Retrieved 2022-07-29 .  
  8. Ogundipe, Samuel (2019-04-22). "How I was born, raised in Nigeria - Atiku" . Premium Times Nigeria . Retrieved 2022-07-29 .  
  9. "The Warrior from Jada ? THISDAYLIVE" . THISDAYLIVE ? Truth and Reason . 2019-02-23 . Retrieved 2022-08-05 .  
  10. Ezeadichie, Christopher (2022-07-18). "BIOGRAPHY AND LIFE OF NIGERIAN BUSINESSMAN AND POLITICIAN, ATIKU ABUBAKAR." . Financial Quest . Retrieved 2022-08-05 .  
  11. Orjinmo, Nduka (2022-07-10). "Atiku Abubakar woos Nigerians with a reminder of the good times" . BBC News . Retrieved 2022-08-11 .  
  12. "ABUBAKAR, Atiku (GCON)" . Biographical Legacy and Research Foundation . 2022-08-08 . Retrieved 2022-08-11 .