Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Aretha Franklin
|
---|
Franklin in 1968
|
?j??ibi
| Aretha Louise Franklin
(
1942-03-25
)
O?u K?ta 25, 1942
Memphis, Tennessee
, U.S.
|
---|
Alaisi
| August 16, 2018
(2018-08-16)
(?m? ?dun 76)
Detroit, Michigan
, U.S.
|
---|
Resting place
| Woodlawn Cemetery
Detroit, Michigan
|
---|
I???
|
- Singer
- songwriter
- actress
- pianist
- activist
|
---|
Igba i???
| 1956 – 2018
|
---|
?m? ilu
| Detroit, Michigan
|
---|
Ololuf??
| |
---|
Aw?n ?m?
| 4
|
---|
Parent(s)
| |
---|
Aw?n olubatan
| |
---|
Awards
| see,
list
|
---|
Musical career
|
Iru orin
| |
---|
Instruments
| |
---|
Labels
| |
---|
Website
| [http:// Official website]
|
---|
|
Signature
|
---|
|
Aretha Louise Franklin
(March 25, 1942 – August 16, 2018) je akorin, akowe-orin, osere, ateduuru, ati alakitiyan eto araalu ara
Amerika
.
[2]
Franklin bere si ni korin lati kekere ninu egbe akorin
gospel
ni ijo
New Bethel Baptist Church
ni
Detroit, Michigan
, nibi ti baba re
C. L. Franklin
ti je oluso-agutan. Nigba to di omo odun 18, o bere si ni korin to gbode. Awon orin re to gbajumo bi "
Respect
", "
Chain of Fools
", "
Think
", "
(You Make Me Feel Like) A Natural Woman
", "
I Never Loved a Man (The Way I Love You)
", ati "
I Say a Little Prayer
", so di akorin agba lagbaye, eyi to je ki o gbajumo bi
Queen of Soul
.