Alaba Lawson

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Alaba Lawson
?j??ibi 18 O?u Kinni 1951 ( 1951-01-18 ) (?m? ?dun 73)
Abeokuta , Ogun State , Nigeria
Oril??-ede Nigerian
Oruk? miran Iyalode Alaba Lawson
Ile??k?? giga
  • Abeokuta Girls Grammar School
  • St. Nicholas Montessori Teachers’ Training College
I???
Igba i??? 1977–present
Employer NACCIMA
Board member of Chairman, Board of Governing Council, Moshood Abiola Polytechnic , Ogun State
Website alabalawson.org

Oloye Alaba Lawson (ti a bi ni Omidan Alaba Oluwaseun Lawson ni ?j? keji-din-logun o?u kinni ?dun 1951) j? ?m? oril?-ede Naijiria; olokoowo nla, oni?owo agba ati ?m?we si ni p?lu. Oun ni o j?? obinrin ak??k?? ti o j? aar? ?gb? NACCIMA ati Alaga Igbim?? aw?n Alakoso ti ile ?ko gbogboni?e, Moshood Abiola ni Ipinl?? Ogun ni oril?-ede Naijiria.

Oloye Lawson ti di ipo aar? agbarij?p? aw?n l?bal?ba to j?? obinrin ni oril?-ede Naijiria (Forum of Female Traditional Rulers in Nigeria).

Ib??r?? igbe aye ati eto ?k? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

A bi Alaba si inu ?bi Jibolu-Taiwo ti ilu Abeokuta , ti i ?e olu ilu fun ipinl? Ogun , nibi ti o ti pari ile-?k? alak?b?r? ati girama ni ile-?k? St. James’ African Primary School, Idi-Ape, Abeokuta laarin ?dun 1957 ati 1962 fun ?k? alak?b?r? ati Ile-?k? girama fun aw?n obinrin (Abeokuta Girls Grammar School), Abeokuta, eleyi ti o pari ni ?dun 1968 [1] ki o to t?siwaju lati l? si ile ?k? fun aw?n oluk?ni ni St. Nicholas Montessori Teachers’ Training College ti o wa ni Prince's Gate, England ni ?dun 1973 ni bi ti o ti peregede ti o si gba iwe ?ri diploma ninu ik?ni (Diploma in Education) [2] .

Aw?n It?kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. https://www.vanguardngr.com/2017/05/naccima-gets-first-female-national-president/
  2. "?da pamosi" . Archived from the original on 2020-02-19 . Retrieved 2022-05-20 .