한국   대만   중국   일본 
Ak? iba - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Ak? iba

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Ak? iba
Akọ ibàKòkòrò aṣòkùnfà láti inú itọ́ òbí ẹ̀fọn tí o ń rìn kiri láyiká ẹ̀fọn
Ak? iba Kokoro a?okunfa lati inu it?? obi ??f?n ti o ? rin kiri layika ??f?n
Kokoro a?okunfa lati inu it?? obi ??f?n ti o ? rin kiri layika ??f?n
Ipins??w?? ati aw?n okunfa ita
ICD/CIM-10 B 50. - B 54. B 50. - B 54.
ICD/CIM-9 084 084
OMIM 248310
DiseasesDB 7728
MedlinePlus 000621

Ak? iba j? aarun akoran lati ara ??f?n ti aw?n eniyan ati aw?n ?ranko miiran ti kokoro ?fa protozoans (iruf?? oni s????li kan kokoro kekeeke ) ti iruf?? kokoro a?okunfa . [1] Ak? iba maa ? fa aw?n aami eyi ti o wa lara ak? iba , igara , bibi ati ??f??ri . Ni aw?n ipo lile o le fa ara pip??n , imu lojiji , daku tabi iku . [2] Aw?n aami w??nyii maa ? saba b??r?? ni ?j?? m??wa tabi m???dogun l??hin igej?. Ni aw?n ti a ko t??ju daradara aarun tun le j?y? ni aw?n o?u meloo boya. [1] Lara aw?n ti o ?????? b?? l??w?? akoran, atun-koran maa ? mu aw?n aami ti ko le jade. Ti di?? ik??jujasi poora ni aw?n o?u si ?dun bi ko basi pe iba k?luni. [2]

Niw??p??, aarun yii maa ? muni nipa igej? l??w?? aabo ??f?n ti o ni akoran An?f??lisi . Igej? yii maa ? mu aw?n kokoro akoran lati it?? ??f?n sinu ??j?? eniyan. [1] Kokoro akoran yii yoo rin kiri l? inu ??d?? nibi ti w?n a ti dagba lati p??si. ??ya maarun Kokoro a?okunfa le ranni ki eniyan tan kiri. [2] ??p?? iku ni o ? waye nipa P. falciparum p??lu P. vivax , P. ovale , ati P. malariae maa ? saba fa iba ti ko lera. [1] [2] Aw?n ??ya P. knowlesi kii saba fa aarun lara aw?n eniyan. [1] A saba maa ? ?awari iba nipa ay??wo ??j?? nipa lilo ohun elo awo kokoro fiimu ??j?? , tabi p??lu idalori antigini - ay??wo i?awari kiakia . [2] Aw?n ilana lilo polymerase itagiji a?okunfa lati ?awari kokoro naa DNA ti di agbekal??, ?ugb??n a ki saba lo ni aw?n agbegbe ti iba ti w??p?? nitori ??w??n ati ipa gbooro lile w?n. [3]

Ijamba ti aarun ni a le dinku nipa did??kun igej? ??f?n nipa lilo aw??n ap??f?n ati oogun ale kokoro , tabi ilana i?akoso ??f?n bii ifunka oogun kokoro ati ilana fun adagun omi. [2] ??p?? aw?n oogun ni o wa id??kun iba lara aw?n arinrin-ajo si ibi ti aarun w??p??. Lilo oogun l??k????kan sulfadoxine/pyrimethamine ni a gba nim??ran ?m?w?? ati ?aaju ib??r?? o?u m??ta oyun ti oyun ni aw?n agbegbe ti iba w??p?? si. Bi ilo ba til?? wa, kosi ojulowo oogun , bi-o-til??-j??pe erongba wa ati ?e ??kan ?l? l??w??. [1] igbaniyanju it?ju iba ni apap?? oogun a?odi si iba ti o ni artemisinin . [1] [2] oogun ikeji lej?? boya mefloquine , lumefantrine , tabi sulfadoxine/pyrimethamine. [4] Quinine p??lu doxycycline alelo bi kobasi artemisinin. [4] A gbaniyanju pe ni agbegbe ti aarun naa ti w??p??, a gb??d?? ?awari iba ki a to b??r?? it?ju nitori ip?si ilodisi oogun . Ilodisi ti gbooro si ??p?? oogun a?odisi iba; fun ap??r?, -a?odisi chloroquine P. falciparum titan kaakiri agbegbe iba, ati a?odisi artemisinin ti di i?oro ni aw?n apa ibikan ni Guusu-ila-oorun A?ia. [1]

Aarun naa titan kiri ni agbegbe orun ati agbegbe orun di?? aw?n ?kun ti o wa ni ayika ti arin ila aaye . [2] Eyi p??lu ??p?? ti Guusu Afirika , Asia , ati Latin Am??rika . Aj? Ilera Agbaye lapap?? pe ni 2012, aw?n i??l?? 207 milionu iba ni o waye. Ni ?dun yi, aarun yi ti pa o keere laarin 473,000 ati 789,000 eniyan, ??p?? ti o j?? aw?n ?m?de ni Afirika. [1] Iba ? waye nibiti o?i wa o si ni ipa odi lori idagba ??r?? aje . [5] [6] Ni Afirika a ti wo lapap?? pe o fa ipadanu $12 bili??nu owo Am??rika ni ?dun kan eyi ti o waye lara igbowo lori it?ju-ilera, ainif?? si i??? ?i?e ati ipalara arin-ajo. [7]

Aw?n it??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 1.5 1.6 1.7 1.8 "Malaria Fact sheet N°94" . WHO . March 2014 . Retrieved 28 August 2014 .  
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 2.5 2.6 2.7 Caraballo, Hector (May 2014). "Emergency Department Management Of Mosquito-Borne Illness: Malaria, Dengue, And West Nile Virus" . Emergency Medicine Practice 16 (5) . http://www.ebmedicine.net/topics.php?paction=showTopic&topic_id=405 .  
  3. Nadjm B, Behrens RH (2012). "Malaria: An update for physicians". Infectious Disease Clinics of North America 26 (2): 243?59. doi : 10.1016/j.idc.2012.03.010 . PMID   22632637 .  
  4. 4.0 4.1 Organization, World Health (2010). Guidelines for the treatment of malaria (2nd ed. ed.). Geneva: World Health Organization. p. ix. ISBN   9789241547925 .  
  5. Gollin D, Zimmermann C (August 2007) (PDF). Malaria: Disease Impacts and Long-Run Income Differences . Institute for the Study of Labor . http://ftp.iza.org/dp2997.pdf .  
  6. Worrall E, Basu S, Hanson K (2005). "Is malaria a disease of poverty? A review of the literature". Tropical Health and Medicine 10 (10): 1047?59. doi : 10.1111/j.1365-3156.2005.01476.x . PMID   16185240 .   open access publication - free to read
  7. Greenwood BM, Bojang K, Whitty CJ, Targett GA (2005). "Malaria". Lancet 365 (9469): 1487?98. doi : 10.1016/S0140-6736(05)66420-3 . PMID   15850634 .