Ajoritsedere Awosika

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??

Ajoritsedere (Dere) Josephine Awosika j?? obinrin oni?owo ara Naijiria to j?? alaga ile ifowopam?? Access plc . [1] ?aaju ipinnu lati pade yii, o j? Akowe Y? ni Federal Ministries of Internal Affairs, Im? & Im?-?r? ati Agbara ni aw?n akoko ori?iri?i.

W?n bi Awosika si Sapele, oje ?m? kefa si ak?k? minisita fun oro aje Nijeriya Alak?k?, Festus Okotie-Eboh, ti w?n seku pa ni 1966. [2] [3] Oje ?kan lara aw?n ?m? ?gb? Olu Pogun Oyinbo Ni Naijiria ati ni Apa iw? Orun Alawodudu Postgraduate College of Pharmacy. Oje ?kan lara aw?n ak?k? jade ni Unifasiti Bradford, ti oti kawe gb?ye Doctorate ni Pharmaceutical Technology.

Aw?n it?kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]