한국   대만   중국   일본 
Aderonke Apata - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Aderonke Apata

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Aderonke Apata
?j??ibi January 20, 1967
Nigeria
Gbajum?? fun Being an LGBT activist and former asylum seeker

Aderonke Apata (ti a bi ni ogunj?? o?u kinni ?dun 1967) j?? ?m? oril??-ede Naijiria ti o ? ja fitafita nipa LGBT, ati ?ni ti o ti n wa ibi aabo t??l??. Aw?n media kaakiri ni w??n m? Aderonke nitori ??ran ibi aabo r? ni ile geesi United Kingdom . [1] [2]

Apata ni oludasil?? ?gb?? alaanu kan ti w??n ? pe ni African Rainbow Family. [3]

Igbesiaye [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Aderonke Apata ni a bi ni ogunj?? o?u kinni ?dun 1967 ni oril??-ede Naijiria . [4] Nigbati Apata wa ni ?m? ?dun m??rindinlogun ni o k??k?? m?? pe alak?meji ni oun. Nitoripe aw?n ?bi Apata ti ? fura pe alak?meji ni Apata, ati wipe aw?n ?bi ?k? r?? bakannaa ? fura sii pe alak?meji ni ati pe o ma n ni aj??ep??, ni o ?e di ?ni ti olopaa ? mu leyin ti won ti rii wipe o ? l??w?? ninu ibalop?? ak?sak? tabi abosabo ninu ile r?. W??n mu Apata l? si ile-?j?? Sharia nibiti w??n ti da ?j?? iku fun un nipa sis? ?? ni okuta pa fun ?i?e agbere ati aj??. [5] [6] Sib??sib??, w??n fagile ?j?? yii nigbati ?niti o duro bii agb?j??ro r? toka si ofin pataki kan lati tako idaj?? yii. Ki o to di wipe w??n gbe e l? si ile-?j??, w??n mu u l? si ?gba ??w??n nibiti w??n ti fii si tubu ojutaye p?lu aw?n ?l??w??n miiran.

Apata sa kuro ni orile-ede Naijiria l? si ilu Londonu, il?? g????si nibiti o ti k??k?? beere fun aabo lab?? ? ??sin ni ?dun 2004 nitori pe o wa lati idile onigbagb??, ?ugb??n ti o j?? wipe ?kunrin musulumi kan ni o ti k??k?? f?? ni ??na ti kot??. O ?e eleyii ni igbiyanju lati pe ki o le b? iba?ep?? ?l??j??-pip?? ti o wa laarin oun ati ?m?binrin miiran m??l??. L??hin ti o ti k??k?? b? ??b?? ni ????meji fun ibi aabo ti w??n si ti k? jal?? fun un, o di ki o maa gbe ni aw?n opopona ni Manchester lati pe ki w??n ma le daapada si orile-ede Naijiria. Ni o?u k?waa ?dun 2012, O lo o?u kan ni aham?? ti oun nikan dawa ni Yari's Wood Immigration Removal Centre gege bii ijiya fun didari ??r??nu alalalafia ni agbegbe naa.

Ni ?dun 2012, l??hin ti w?n mu Apata pe o ? ?e i??? gege bii alakoso olut??ju p??lu ayederu fisa, o tun gbiyanju lati beere fun ibi aabo nitori pe o ? b??ru lati pada wa si orile-ede Naijiria nibiti w??n ti le ?e inunibini sii nipa fifi ??sun kan an nipa ????? ibalop?? r?. Ibi aabo ti o beere fun yi ati ibi aabo miiran ti o beere fun ni w??n k?? jal?? fun un ni ?dun 2014 ati ni ?j?? kinni o?u k?rin ?dun 2015 ni t??lent??le nitori pe ile-i???, eyi tii ?e ????ka kan lab?? igbim?? minisita ni ile geesi ko gbagb?? pe alak?meji ni Apata nitori pe o ti ni aj??ep?? p?lu ?kunrin kan t??l?? ti o si ti bi aw?n ?m? fun okunrin naa. [7] [8] [9] Ni ?dun 2014, Apata s? wipe oun yoo fi fidio ti yio han gbangba lati j??risi ibalop?? oun ran??? si Home Office yii. Eyi lo mu ki bibeere fun ibi aabo r? yii gba atil??yin kaakiri, p??lu bi aw?n eniyan ?e fesi nipa kik? aw?n iwe ??b?? eyiti w??n gba ?g???g??run un ?gb??run aw?n ibuw??lu lapap??. Lehin naa, o ku di?? ki w??n da Apata pada wa si orile-ede Naijiria, ?ugb??n w??n s? fun un nigbati o wa ?k?? de papak?? ofurufu na wipe w??n ti fagile irin-ajo ?k?? ofurufu r? si orile-ede Naijiria.

Ni ?j?? k?j? o?u k?j? ?dun 2017, lehin ?dun m??tala ti ip??j?? ti ? waye ati lehin fifi ?j?? kot??mil??run tuntun ti Apata pe si opin o?u keje, Home Office fun un ni aaye ni il?? geesi gege bii ?ni ti o sa asala. Iy????da ibi aabo ti w??n fun Apata ni o pari ni ?dun marun un, ?ugb??n lehin naa o ni anfani lati beere fun gbigbe il?? g????si titilai. [10]

Igbesi aye ara ?ni [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Lehin ti Apata k?? ??k?? jade ni oril??-ede Naijiria , o ni ??r??binrin kan ti w??n j? gbe pap?? ni iy??wu kanna.

Ni ?dun 2005, ay??wo fi han pe Apata ni arun ti w??n ? pe ni Post-traumatoc stress disorder (PTSD). Apata gbiyanju lati gba ??mi ara r?? nigbati o wa ninu tubu ti o ?koju ?j?? idapada si orile-ede r?. Ni ?dun 2012, w??n pa alagba?ep?? r? obinrin t??l?? ninu i???l?? oju-lalakan-fin???ri kan. Arakunrin Apata ati ?m? ?dun m??ta ni w??n tun pa ninu aw?n i??l? oju-lalakan-fin???ri.

Lati ?dun 2015 ni Apata ati Happiness Agboro, ?ni ti w??n ti fun ni a?? lati gbe ilu lab?? ? pe o ?sa asala fun emi r?? ni il?? geesi eyi ti o da lori ibalop?? r?, ti gba lati f?? ara w??n. Lati bii ?dun 2017 ni Apata ti ? gbe il?? geesi.

Aw?n ami ??y? ati iyin [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  • LGBT Positive Role Model Award from the 3rd National Diversity Awards (2014). [11]
  • Activist of the Year from the 24th Sexual Freedom Awards (2018). [12]

Aw?n it??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. Taylor, Diane (2017-08-14). "Nigerian gay rights activist wins UK asylum claim after 13-year battle" . the Guardian . Retrieved 2021-09-22 .  
  2. "Why the Home Office rejects so many LGBTQ asylum claims" . City, University of London . 2020-09-23 . Retrieved 2021-09-22 .  
  3. "Nigerian LGBTQ activist granted asylum in UK after 13-year legal battle" . NBC News . 2017-08-14 . Retrieved 2021-09-22 .  
  4. "Aderonke APATA - Personal Appointments (free information from Compani…" . archive.ph . 2021-01-10 . Retrieved 2021-09-22 .  
  5. Dugan, Emily (2014-06-09). "Gay Nigerian asylum-seeker in fight to stay in the UK" . The Independent . Retrieved 2021-09-22 .  
  6. Dunt, Ian (2015-12-27). "Can you prove you're gay? Last minute legal battle for lesbian fighting deportation to Nigeria - Home Affairs" . politics.co.uk . Archived from the original on 2015-12-27 . Retrieved 2021-09-22 .   Unknown parameter |url-status= ignored ( help )
  7. Ashton, Jack (2017-08-14). "Gay rights activist who judge accused of 'faking' her sexuality wins 13-year legal battle for asylum in UK" . The Independent . Retrieved 2021-09-22 .  
  8. Dugan, Emily (2015-04-03). "A High Court judge just told a Nigerian gay rights activist she is not a proper lesbian" . The Independent . Retrieved 2021-09-22 .  
  9. "Lesbian Nigerian woman told: 'Prove you're gay to stay in Britain' - …" . archive.ph . 2015-04-22 . Retrieved 2021-09-22 .  
  10. Hornall, Thomas; Association, Press (2017-08-14). "Nigerian Lesbian Granted Asylum After 13-Year Battle Against Deportation" . HuffPost UK . Retrieved 2021-09-22 .  
  11. "National Diversity Awards" . Wikipedia . 2014-01-29 . Retrieved 2021-09-22 .  
  12. "2018 Finalists" . Sexual Freedom Awards . 2018-11-15 . Retrieved 2021-09-22 .