한국   대만   중국   일본 
Adem??la Adebise - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Adem??la Adebise

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Adem??la Adebise
?j??ibi 1966 (?m? ?dun 57–58)
Ipinl?? Eko ,
Ile??k?? giga
Igba i??? 1988- doni
Gbajum?? fun Wema Bank MD/CEO

Adem??la Adebise ni o j?? Adari agba ati Olootu agba yan yan fun ile-ifowopam?? Wema Bank Plc . [1]

Igba Ewe r?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

W??n bi Adebisi ni w??n bi ?j?? K?kanlel??gb??n o?u K?waa ?dun 1966 , ni Ipinl?? Eko sinu ?bi ??gb??ni ati arabinrin Adegoke Adebise. O l? si ile-??k?? Baptist Academy ti o wa ni ilu Suurulere ni aarin ?dun 1972 si ?dun 1978, ti o si l? si ile-??k?? figba Yunifasiti ti Eko nibi ti o ti k??k???? nipa im?? ??r? K??mputa laarin 1983 si ?dun 1987.

Adebise gba oye digiri keji ninu im?? Business Administration (MBA) ni ile-??k?? Lagos Business School ti o si ile-??k?? Advanced Management Program (AMP) ti o wa ninu ile-??k?? Harvard Business School .

I??? r?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Adebise ti ?i??? p??lu ile i??? Information Technology Company ti o wa ni oril??-ede Naijiria g??g?? bi Programmer ati alaaye im?? K??mputa ni ?dun 1988 ?aaju ki o b??r?? si ?i?e nile ifowo-pam?? Stanbic IBTC ni ??ka eto im? ??r?. ??w??, lara aw?n ile-i??? ti o tun ti ?i??? ni:

? Olori l??ka ??to ??r?? im?? ??r? ati ??ga agba fun eto i?una (CFO) ti ile Ifowo-pam?? Chartered Bank (1989 si 2000)

? Igba keji Adari agba nile ifowo-pam?? National Bank supervised Risk Management, Treasury and Corporate Banking (2001 - 2005)

? ??ga agba ti ile ifowo-pam?? ti National Bank (2005).

? Adari agba l??ka eto i?una ati i??? akan?e ni ile-i??? Accenture (2005)

? Adari ati Olootu agba fun ile-ifowo-pam?? South Bank , Igba keji Adari agba ti o mojuto ile ifowopam?? Wema Bank _ (2017). Adebise di Olootu agba l??yin ti Adari agba ??gb??ni ???gun Oloetuyi f??yin ti kuro nile ifowo-pam?? We ma Bank ni ?j???? Kini o?u K?waa ?dun 2018 l??yin ti Ile Ifowo-pam?? agba il?? Naijiria ti f?w?? si ki o di ??ga agba. [2] Bakan naa ni o tun ti ?i??? p??lu aw?n ile-i??? olokowo bi Nigeria Inter-Bank Settlement System Plc (NIBSS) , AIICO insurance Plc ati AIICO Pension Managers Limited

Aw?n ibi ti o j?? ?m? ?gb?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

? Institute of Chartered Accountants of Nigeria

? The Chartered Institute of Taxation of Nigeria

? The Chartered Institute of Bankers of Nigeria

? The Institute of Directors of Nigeria

? The Computer Professionals (Registration Council of Nigeria) CPN

Aw?n ami-?y? r?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Business Day Award for the Top 25 CEOs in Nigeria (2009)

Igbe aye r?? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Adebise ?e igbeyawo p??lu arabinrin Adejum??k??, w??n si bim? m??ta.

Aw?n It??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]