한국   대만   중국   일본 
AbdulRahman AbdulRasaq - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

AbdulRahman AbdulRasaq

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??


Abdulrahman Abdulrazaq
Gomina ipinl?? Kwara
L??w??l??w??
O gun ori aga
29 May 2019
Deputy Kayode Alabi
Asiwaju Abdulfatah Ahmed
Aw?n alaye onitohun
?j??ibi 5 O?u Keji 1960 ( 1960-02-05 ) (?m? ?dun 64)
Zaria , Northern Nigeria|Northern Region, British Nigeria (now in Kaduna State , Nigeria)
?gb?? olo?elu All Progressives Congress (APC)
(Aw?n) ololuf?? Olufolake Davies
Occupation Politician
Website Campaign website

AbdulRahman AbdulRazaq (ojoibi 5 February 1960) je oloselu ara Naijiria, eni ti o ti se gomina ipinle Kwara lati odun 2019 titi di ?dun 2027. [1] [2]

Igbesi aye ib?r? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Won bi ni Rahmani ni ijoba ibile Ilorin West . AbdulRahman je omo Alh. AGF AbdulRazaq SAN. , agb?j?ro ariwa ak?k? ni Nigeria. [3]

I??-?i?e [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Oselu [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Odun 1999 lo darapo mo oselu nigba ti Naijiria pada si inu ijoba tiwantiwa. Ni odun 2011, ko yege fun un lati dije du ipo gomina ni Ipinle Kwara lori egbe Congress for Progressive Change (CPC) o si tun dije laibobo fun Kwara Central Senatorial District ni egbe Peoples Democratic Party (PDP) ni odun 2011 ati ?dun 2015. O bori ninu idibo alak?b?r? gomina ti Gbogbo Progressive Congress fun Ipinle Kwara ni O?u K?wa ?dun 2018. [4] [5] [6]

W??n di bo yan an g??g?? bi gomina ipinl?? Kwara nibi idibo gomina ?dun 2019 ti o waye ni ?j?? k?san-an o?u k?ta ?dun 2019 ti w??n si bura ni ?j?? k?kandinl??gb??n o?u karun-un ?dun 2019. Ni O?u Karun ?j? 24, ?dun 2023, o di alaga tuntun ti Apej? Aw?n Gomina Naijiria ni ipade ita gbangba ti aw?n gomina ti o waye ni Abuja ti o t?le gomina t?l? ti Ipinle Sokoto , Aminu Tambuwal, ti o di alaga ni ?dun 2022, pelu gomina ipinle Oyo , Seyi Makinde gege bi igbakeji alaga. [7]

Aw?n it?kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]