한국   대만   중국   일본 
?k??-al?b?? Ofurufu Atlantis - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

?k??-al?b?? Ofurufu Atlantis

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Atlantis
OV-104
Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Atlantis
Atlantis being rolled out to launch pad 39B in preparation for STS-115 .
OV designation OV-104
Country United States
Contract award January 29, 1979
Named after RV Atlantis
Status Active, in orbit
First flight STS-51-J
October 3–7, 1985
Last flight STS-132
May 14–26, 2010
Number of missions 31
Crews 185
Time spent in space 282 days, 28 seconds [1]
Number of orbits 4,462
Distance travelled 115,770,929 miles (186,315,250 km) as of STS-129 [2]
Satellites deployed 14
Mir dockings 7
ISS dockings 10

?k??-ayara Ofurufu Atlantis ti o ti lo si inu ofurufu lati nnkan bi ose meji ni o pada si ile aye ni Edwards Airforce Base, California, U.S.A. ni oni ojo Ketalelogun osu kefa odun 2007. Gbogbo awon mejeeje ti won wa ninu re ni won ba a de. Sunita Williams naa ti gunle si ile aye. Oun ni obinrin ti o pe ju ni oju ofurufu. Ojo marundinlogowaa (195 days) ni o gbe ni oju ofurufu. Oun naa ni obinrin ti o rin ni oju ofurufu ju.


Itokasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. Harwood, William (October 12, 2009). "STS-129/ISS-ULF3 Quick-Look Data" . CBS News . http://www.cbsnews.com/network/news/space/129/129quicklook2.pdf . Retrieved November 30, 2009 .  
  2. "STS-132 Press Kit" (PDF) . Archived from the original (PDF) on 2018-12-25 . Retrieved 2010-05-07 .  

Adak?:Space Shuttle Mission Link Adak?:Space Shuttle Atlantis Adak?:Space shuttle Adak?:Space Shuttles